Muna (rapper)
Munachi Gail Teresa Abii Nwankwo jẹ́ olórin, akọrin, agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí telefision àti osere ni ìpínlè Nàìjíríà . Ó gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Imo ni Nàìjíríà.[1]
Munachi Gail | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Munachi Gail Teresa Abii Nwankwo Port Harcourt, Rivers State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Rap/hip hop recording artiste, songwriter, tv presenter, model |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005-2015 |
Title | Most Beautiful Girl in Nigeria (MBGN) 2007 |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọn bíi sì ilẹ̀ Port Harcourt, ibẹ̀ ni ó sì gbé dàgbà. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Federal Government Girl's College ni Abuloma. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Benson Idahosa University níbi tí ó tí ká International relations and Diplomacy.[2]
Ìṣe
àtúnṣeÓ gbé ìgbà o ròkè nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà ní ọdún 2007 ní ìgbà tí ó sì wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga.[3][4] Óun ló ṣe aṣojú fún Nàìjíríà nínú ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni àgbáyé.[5] Ní ọdún 2009, òun àti ẹni tí ó gbé ìgbà o ròkè ní ọdún 2000 fún ìdíje obìnrin tí ó rẹwà jùlọ ni Nàìjíríà, Matilda Kerry jọ ṣíṣe pọ̀ láti sọ̀rọ̀ nípa àrùn jẹjẹrẹ.[6]
Munachi je olórin, orúkọ orí ìtàgé rẹ ni Babyrella kí ó tó padà wá yí sì Múná.[7] Ó ti kọ orin fún àwọn olórin bíi J Martins àti Waje. Ó sì má ṣe kópa nínú fíìmù fún àwọn olórin, ó wá nínú fíìmù Ifunaya tí àwọn P Square ṣe.
Ni oṣù kẹfà ọdún 2010, Muna darapọ̀ mọ ilé iṣẹ́ Ayọ̀ Shonaiya RMG company níbi tí ó tí ṣe àwọn orin rẹ̀ bíi The Goddess àti The hustler. [8][9][10][11]
Ní ọdún 2011, Múná darapọ̀ mọ ilé iṣẹ́ Unilever níbi tí ó tí ṣe àwòṣe fún Lux.[12] Ó ṣe atọkun fún eré orí telefision tí Malta Guinness Street Dance Africa.[13]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Meet the Most Beauriful Girls in Nigeria". buzznigeria.com. Retrieved 6 November 2019.
- ↑ Felicia, Onuigbo (August 9, 2018). "30Yrs Old Ex Beauty Queen". gistmania. Retrieved 6 November 2019.
- ↑ MBGN website Archived 1 May 2008 at the Wayback Machine.
- ↑ "Vanguard interview with Munachi". Archived from the original on 2013-03-07. Retrieved 2020-05-11.
- ↑ "Welcome to Linda Ikeji's Blog". lindaikeji.blogspot.com. Retrieved 2017-08-29.
- ↑ Alex, Samade (2010-01-16). "Handing over a relief, Says Munachi Abii". Vanguard. Retrieved 2017-08-29.
- ↑ "Modern Ghana - Breaking News, Ghana, Africa, Entertainment" (in en-GB). ModernGhana.com. http://www.modernghana.com/movie/4032/3/munachi-abii-ready-for-music-career.html.
- ↑ Linda Ikeji (27 June 2010). "Welcome to Linda Ikeji's Blog: Munachi Abii signs with RMG company". Lindaikeji.blogspot.co.uk. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ "Munachi Abii Steps Up Music Career". PM NEWS Nigeria. 2010-07-01. Retrieved 2017-08-29.
- ↑ "OFFICIAL RELEASE: Muna - I Feel Real (The David Guetta Mix)". NotJustOk. 2010-09-16. Archived from the original on 2017-08-29. Retrieved 2017-08-29.
- ↑ "Muna - Killer Queen ft Buckwylla". NotJustOk. 2011-01-09. Retrieved 2017-08-29.
- ↑ "BN Exclusive: Munachi as the new Face of LUX Soap – A Sneak Peek of the TV & Print Ads". BellaNaija. 12 May 2011. Retrieved 19 April 2014.
- ↑ Johnson, Ayodele (August 2, 2016). "Ex Beauty Queen becomes TV Presenter". Pulse.ng. Retrieved 6 November 2019.