Naija news
Naija News jẹ́ ile-ise oni ìwé ìròyìn ẹ̀rọ ayélujára tí Nàìjíríà. Wọ́n dáa sílè ni ọdún 2016 nípa ọgbeni Opemipo Olawale Adeniyi. [1]
Naija-News-Logo.png | |
---|---|
URL | naijanews.com |
Type of site |
|
Registration | None |
Available language(s) |
|
Current status | Active |
History
àtúnṣe
Wọ́n dá Naija News sílẹ̀ ní ọdún 2016 pẹ̀lú ati leyin Polance media Limited. Ní ọdún 2021, ile-ise yìí kó lọ sí ikoyi ni ìpínlè Eko láti tẹsiwaju nínú ìṣe wọn.
- ↑ "About Naija News". Naija News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 July 2017. Archived from the original on 3 November 2021. Retrieved 22 November 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Polance Media launches online newspaper, Naija News". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 December 2016. Archived from the original on 26 December 2021. Retrieved 22 November 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Wale Adeniyi’s Rebrands Media Platform, Moves Corporate Headquarters To Ikoyi Lagos". Leadership (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 25 December 2021. Retrieved 22 December 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)