Narok (tí àwọn mìíràn mọ̀ sí Ìlú Narok) jẹ́ ìlú kan ní ìwọ̀ oòrùn Nairobi tí ó sì ń gbé ọ̀rọ̀ ajé Kenya ga ní gúúsù ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀ èdè náà. Narok jẹ́ Olú-ìlú Narok County ó sì jẹ́ àárín ètò ọ̀rọ̀ ajé agbègbè. Ìlú náà ní olùgbé tí ó tó ẹgbẹ̀rún ogójì ènìyàn. Ìlú Narok ni ìlú tí ó tóbi tí ènìyàn má kàn kẹ́yìn tí ènìyàn bá ń lọ láti Nairobi lọ sí pákì Maasai Mara àti Keekorok Lodge. Ọ̀nà tí owó fi ń wọlé ní ìlú Narok láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn ni iṣẹ́ àgbẹ̀, kùsà àti pápá ìṣeré bọ́ọ̀lù tí ó wà níbẹ̀

Narok
Town
Lua error in Module:Location_map at line 420: attempt to compare nil with number.
Coordinates: Lua error in package.lua at line 80: module 'Module:ISO 3166/data/KE' not found.
Country Kenya
CountyNarok County

Ètò ẹ̀kọ́ ìlú Narok

àtúnṣe

Ìlú Narok ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ìwé aládàáni àti ti ìjọba.

Ilẹ́ ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ ti ìjọba

àtúnṣe
  • Masikonde Primary School
  • Ole Sankale Boarding School
  • St. Mary's Primary School
  • St. Peter's Primary
  • Lenana Primary School
  • Ilmashariani Primary School

Private Primary Schools:

Ilé ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ aládàáni

àtúnṣe
  • Narok Boys' High School.
  • Maasai Girls' High School.
  • Ole Tipis Secondary School
  • St Mary's Secondary School.

Private Secondary Schools:

  • St. Stephen Nkoitoi Secondary School
  • Limanet Secondary School

Colleges

àtúnṣe
  • Narok Teachers Training College
  • Narok West Technical Training Institute
  • Ludepe Teachers College [1]
  • Lusaka Institute of Science and Technology
  • Narok West Institute of Professional Studies [2]
  • WE College [3]

Yunifásítì

àtúnṣe

Ilé ìwé Kristíẹ́nì

àtúnṣe
  • Bible College, Bisset Bible College

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ludepe Teachers College - Kenyaplex.com". www.kenyaplex.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-07-23. Retrieved 2019-08-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Nyamwembe, Denis. "KASNEB accredited institutions: Conditions for Accreditation, Full Accreditation, Interim Accreditation and Accreditation in Progress | Jambo News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-08-18. Retrieved 2019-08-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Kenya: First Lady Champions Education Opportunities for Vulnerable Girls and Women". allAfrica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-18. Archived from the original on 2019-07-19. Retrieved 2019-08-18.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Kiplagat, Robert (2019-02-09). "Disquiet at Maasai Mara University following corruption exposé". Standard Media (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-02-01. Retrieved 2020-02-28.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)