Narok Museum jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní Narok, orílẹ̀ èdè Kenya.[1] Wọ́n dá musíọ́mù náà kalẹ̀ láti ṣe ìfihàn ère, àwòrán àti àwọn ǹkan míràn tí àwọn agbègbè tí ó ń sọ èdè Maa ń ṣe.[2]

Narok Museum
Building
LocationNarok, Kenya
OwnerNational Museums of Kenya

Ilé tí musíọ́mù náà wà jẹ́ ilé tí wọ́n kọ́ tẹ́lẹ̀rí fún àwọn ará ìlú.[3] Musíọ́mù náà kún fún àwọn ǹkan tí wọ́n ti ń gbà láti ọdọọdún sẹ́yìn.[2]

Àwọn ohun tí ó wà níbẹ̀

àtúnṣe

Musíọ́mù náà ní àwọn èlò tí àwọn ènìyàn Maasai láyé àtijọ́, àti àwọn ère àwọn agbègbè tí ó ń sọ èdè Máa, pẹ̀lú pẹ̀lú àwọn Ndorobo, Samburu àti Njemps.[4] Ó tún ní àwọn àwòrán Joy Adamson tí ó yà ní àwọn ọdún 1950s.[3] Musíọ́mù náà ní àwọn àwòrán nípa àṣà àwọn ènìyàn Massai.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Narok - Historical Background Archived 2007-12-18 at the Wayback Machine.
  2. 2.0 2.1 Masago, Morompi Ole, Kweingoti G. Reuben, and Sambu Alice. "Investigating the Effects of Covid-19 pandemic on Narok County’s Tourism and Hospitality Sectors."[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] (2020).
  3. 3.0 3.1 Kenya. Philip Briggs, Lizzie Williams, Dorling Kindersley Limited (Reprinted with revisions ed.). London. 2013. ISBN 978-1-4654-1786-2. OCLC 861227804. https://www.worldcat.org/oclc/861227804. 
  4. Otieno, Kepher. "Jaramogi Museum to benefit from Sh8 million renovation". The Standard (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-27.