National Library of Mauritania

Ilé ìkàwé orílẹ̀ èdè Mauritania (English: National Library of Mauritania, Arabic: المكتبة الوطنية الموريتانية) jẹ́ ilé ìkàwé kan tí ó wà Nouakchott, Mauritania nínu ilé kan náà tí National Museum of Mauritania wà.[1][2] Ó ní tó àwọn ìwé ẹgbẹ̀rún mẹ́wá àti òṣìṣẹ́ ọ̀kànlélógójì.[2][3] Ilé ìkàwé náà ní ẹ̀ka méje.[3]

National Library of Mauritania
Building
LocationNouakchott
Coordinates18°05′09″N 15°58′30″W / 18.0859°N 15.975°W / 18.0859; -15.975Coordinates: 18°05′09″N 15°58′30″W / 18.0859°N 15.975°W / 18.0859; -15.975

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "List of Addresses of the Major Libraries in Africa". ECA Library. Archived from the original on 2012-06-30. Retrieved 2012-10-16.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. 2.0 2.1 "Bibliothèque Nationale de Mauritanie -- National Library of Mauritania". librarytechnology.org. OCLC 51842796. Retrieved 2016-07-05. 
  3. 3.0 3.1 "Bibliothèque Nationale de Mauritanie". Anna Lindh Foundation. Egypt. Archived from the original on 2017-08-17. Retrieved 2016-07-05.