National Museum of Mauritania
National Museum of Mauritania, tí àwọn ènìyàn tún mọ̀ sí National Museum of Nouakchott (Faransé: Musée National de Nouakchott), jẹ́ musíọ́mù àgbà orílẹ̀ èdè Mauritania, tí ó wà ní Nouakchott. Ó wà ní gúúsù apá ìwọ oòrùn Hotel Mercure Marhaba, ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà Hotel de Ville, àríwá ìwọ̀ oòrùn Parc Deydouh, àti àríwá Mosque Ould Abas.[1]
National Museum of Mauritania Musée National de Nouakchott | |
---|---|
Ilé musíọ́mù náà | |
Building | |
Location | Nouakchott, Mauritania |
Coordinates | 18°5′8″N 15°58′29″W / 18.08556°N 15.97472°WCoordinates: 18°5′8″N 15°58′29″W / 18.08556°N 15.97472°W |
Musíọ́mù náà jẹ́ ilé fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohùn pàtàkì ayé àtijó tí wọ́n padà wú jáde láti inú ilẹ̀.[2]
Ilé Musíọ́mù náà
àtúnṣeIlé musíọ́mù náà jẹ́ ilé alájà méjì tí àwọn aráa China kọ́ in 1972. Ilé náà tún jé ilé fún Mauritanian Institute of Scientific Research, the Mauritanian Manuscripts Conservation Centre àti Ilé ìkàwé Mauritania.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ The National Museum of Mauritania Archived 2021-07-09 at the Wayback Machine..
- ↑ "Mauritania museums". Africa.com. Archived from the original on 1 January 2013. Retrieved 10 March 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)