Ndubuisi Ekekwe /θj/ (tí a bí ní July 1975) jẹ́ oníṣòwò orílẹ̀-èdè Naijiria.[1] Òun ni olùdásílẹ̀ First Atlantic Semiconductors & Microelectronics.[2] Ní ọdún 2020, ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn The Guardian (Nigeria) tò ó pọ̀ mọ́ ọ̀kan lára àwọn ọgọ́fà ọmọ Nàìjíríà tó ń ṣịṣẹ́ ribiribi.[3]

Ndubuisi Ekekwe
ÌbíIsuikwuato, Nigeria
PápáElectrical and Computer Engineering
Ilé-ẹ̀kọ́
Ibi ẹ̀kọ́
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síWorld Economic Forum Young Global Leader

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "London-Based Planet Earth Institute Honors Ndubuisi Ekekwe as Tech "Pioneer" - Tekedia" (in en-US). Tekedia. 2017-12-17. https://www.tekedia.com/london-based-planet-earth-honors-ndubuisi-ekekwe-as-a-tech-pioneer/. 
  2. "Ndubuisi Ekekwe - The Solutions Journal" (in en-US). The Solutions Journal. https://www.thesolutionsjournal.com/author/ndubuisi-ekekwe/. 
  3. "60 Nigerians Making "Nigerian Lives Matter" In 60 Years". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-04. Archived from the original on 2021-09-20. Retrieved 2021-05-27.