Ajagun Ojúomi Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Nigerian Navy)
Ile-ise Ajagun Ojúomi Nàìjíríà (tabi Nigerian Navy (NN)) ni apa ajagun ojuomi ile-ise ologun Naijiria. Ajagun Ojúomi Nàìjíríà ni ikan ninu awon ajagun ojuomi to tobijulo ni Afrika. O ni awon omo-ogun to to 7 000 personnel, ti Ile-ise Eso Eti-Odo (Coast Guard) na je ikan ninu re.
Nigerian Navy Ajagun Ojúomi Nàìjíríà | |
---|---|
Ìgbéṣe | 1958-present |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Irú | Navy |
Motto | Onward Together |
Àwọn apàṣẹ | |
Current commander |
Rear Admiral Dele Joseph Ezeoba |
Àmì-ẹ̀ṣọ́ | |
Naval Ensign | |
Naval Ensign (1960-1998) |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |