Nii Amaa Ollennu
Raphael Nii Amaa Ollennu (tí a bí ní 21 May 1906, tí ó sì kú ní 22 December 1986)[2] jẹ́ agbẹjẹ́rò àti adájọ́ tó dí adájọ́ àgbà fún Ilé-ẹjọ́ gíga jùlọ ní orílẹ̀-èdè Gánà láti ọdún 1962 sí 1966. Òun sì ni Ààrẹ ilẹ̀ Ghánà nígbà ìjọba olómìna kejì, láti 7 August 1970 sí 31 August 1970 àti agbọ̀rọ̀sọ ní ilé-ìgbìmọ̀ aṣòfin ti ìlú Ghana láti 1969 wọ 1972.
Nii Amaa Ollennu | |
---|---|
Fáìlì:RNAOllennu.png Nii Amaa Ollennu | |
President of Ghana Acting Second Republic | |
In office 7 August 1970 – 31 August 1970 | |
Alákóso Àgbà | Dr. K.A. Busia |
Asíwájú | A.A. Afrifa |
Arọ́pò | Edward Akufo-Addo |
Speaker of the Parliament of Ghana Second Republic | |
In office 1 October 1969 – 12 January 1972 | |
Asíwájú | Kofi Asante Ofori-Atta (First Republic) |
Arọ́pò | Jacob Hackenburg Griffiths-Randolph Third Republic |
Justice of the Supreme Court of Ghana | |
In office 1 September 1962 – 1966 | |
Appointed by | Kwame Nkrumah |
Ààrẹ | Kwame Nkrumah |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Accra, Gold Coast[1] | 21 Oṣù Kàrún 1906
Aláìsí | 22 December 1986[1] | (ọmọ ọdún 80)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Ghanaian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Emily Jiagge Charlotte Amy Sawyerr Nana Afua Frema (Queen-mother of Wenchi) |
Ẹbí |
|
Àwọn ọmọ | Amerley Ollennu (daughter) |
Education | |
Profession |
Ìgbésí ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Ollennu sí Labadi, ní ìlú Accra, ní ọdún1906, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ènìyàn Ga.[3] Àwọn òbi rẹ̀ ni Wilfred Kuma Ollennu àti Salomey Anerkai Mandin Abbey.[4] Ollennu lọ sí ilé-ìwé Salem School ní ìlú Osu .[5] Ó ka ẹ̀kọ́ girama níAccra High School.[6] Lára ẹ̀kọ́ ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ rẹ̀ wá láti Presbyterian Training College ní Akropong, tó wà ní apá Ìlà-Oòrùn orílẹ̀-èdè Ghana, níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ pedagogy àti theology.[7] Ó lọ sí England láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ jurisprudence ní Middle Temple, London. Wọ́n sì pè é wọ ilé-ẹjọ́ ní ọdún 1940 lẹ́yìn tó fi oṣù méjìdínlógún kẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́dún mẹ́ta. Ó jáde pẹ̀lú èsì tó tayọ, èyí sì mu gba ìdánimọ̀ láti ọ̀dọ̀ ìgbìmọ̀ Queen.[8]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Review of Ghana Law, Volume 12 Archived 2017-09-14 at the Wayback Machine., General Legal Council, 1980.
- ↑ "Rulers - Ghana". List of heads of state and heads of Government. Rulers.org. Archived from the original on 2007-04-03. Retrieved 2007-03-24. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Lentz, Harris M. (4 February 2014). Heads of States and Governments Since 1945. Routledge. p. 317. ISBN 978-1-134-26490-2. https://books.google.com/books?id=D6HKAgAAQBAJ&q=Edward+Akufo-Addo+born&pg=PA317.
- ↑ "Nii Ollennu - Historical records and family trees - MyHeritage". www.myheritage.com. Archived from the original on 2018-02-05. Retrieved 2018-02-04. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Osu Salem". osusalem.org. Archived from the original on 2017-03-29. Retrieved 2017-06-24. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ The International Who's Who 1983-84. Europa publications. 1983. p. 1026. ISBN 9780905118864. https://books.google.com/books?id=_xJ4R0t9G3oC&q=Ollenu+Nii+Amaa+wilfred.
- ↑ Dr. Kwame Okoampa-Ahoofe, Jr (31 August 2006). "When Dancers play Historians and Thinkers - Part 10". Feature Article. Modern Ghana Homepage. Archived from the original on 27 September 2007. Retrieved 2007-03-25. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Destined to be a Lawyer - College of Law - University of Idaho". www.uidaho.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-06-29. Retrieved 2017-09-14. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)