Nkiru Sylvanus
Nkiru Sylvanus tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kẹ́rin ọdún 1982, jẹ́ òṣèré àti olóṣ̀èlú. Ó tí kópa nínú eré tí ó tó àádójé tí ó sì ti gba àmì-ẹ̀yẹ tí Africa Magic Viewers Choice Awards fún Òṣèré léwájú tí ó peregedé jùlọ nínú ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards. [1] [1][2][3][4]
Nkiru Sylvanus | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Nkiru Sylvanus 21 Oṣù Kẹrin 1982 Ìpínlẹ̀ Abia |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Enugu State University of Science and Technology |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1999-Present |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí Sylvanus ní ìlú Osisioma, ní Ìpínlẹ̀ Abia. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákòọ́bẹ̀rẹ̀ ti Ohabiam àti ilé-ẹ̀kọ́ girama ní agbègbè kan náà. Ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásitì gbogbonìṣe ti Ìpínlẹ̀ Enugu tí ó kẹ́kọ́ gboyè nínú ìmọ̀ ìbára-ẹní-sọ̀rọ̀.[5][6][7]
Iṣé rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré
àtúnṣeSylvanus bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe ní dédé ọmọ ọdún mẹ́tàdínlógún ní ọdún 1999. Ó ti kópa nínú eré tí ó tó àádóje.[1][8][9] Ó ti fara hàn nínú ìwé-ìròyìn The Guardian's ní ọdún 2017 àti 2018 gẹ́gẹ́ bí Gbajúmọ jùlọ lórí ìwé-ìròyìn.[10][11]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré
àtúnṣeNí ọdún 2011, wọn yàn án Sylvanus sí ara àwọn ìgbìmọ̀ tí Gómìnà Rochas Okorocha gégẹ́ bí olùbádámọ̀ràn sí Ìpìnlẹ̀ Èkó lórí ọ̀rọ̀ àwùjọ.[12][13][14][15]
Ìjínigbé rẹ̀ ní ọdún 2012
àtúnṣeWọ́n jí Sylvanus gbé ní ọjọ́ kẹẹ̀dógún oṣù Kejìlá ọdún 2012 tí àwọn ajínigbé náà sì bèrè fún ọgọ́rún mílíọ́nù náírà ( ₦100,000,000) gẹ́gẹ́ bí ìwé-ìròyìn Vanguard tí sọ ṣáájú kí wọ́n tó dá wọn sílẹ̀.[7] [16][17][18][19][20] It was reported by Nigerian media houses that on December 21, 2012 at 10:30pm, Sylvanus was released from her kidnappers.[19]
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣe- Òṣèrébìnrin tó peregedé jùlọ nínú ayẹyẹ Africa Magic Viewers Choice Awards
- Òṣèrébìnrin aléwájú tó peregedé jùlọ nínú ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards[1]
Ìgbé ayé rẹ̀
àtúnṣeNí ọdún 2014, Sylvanus ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Stanley Duru, àmọ́ wọ́n pín yà ní ọdún 2019. [21][22][23]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣe- Final Tussle (2008)
- Life Bullets (2007)
- Fine Things (2007)
- No More Love (2007)
- Secret Pain (2007)
- She Is My Sister (2007)
- The Last Supper (2007)
- Treasures Of Fortune (2007)
- Alice My First Lady (2006)
- Buried Emotion (2006)
- Divided Attention (2006)
- Pastor’s Blood (2006)
- Serious Issue (2006)
- Sweetest Goodbye (2006)
- What A Mother (2005)
- Dangerous Mind (2004)
- Hope Of Glory (2004)
- King Of The Jungle (2004)
- My Blood (2004)
- Queen (2004)
- The Staff Of Odo (2004)
- Unconditional Love (2003)
- Egg Of Life (2003)
- Green Snake (2003)
- Six Problems (2003)
- Holy Violence (2003)
- Last Weekend (2003)
- Onunaeyi: Seeds Of Bondage (2003)
- The Only Hope (2003)
- A Cry For Help (2002)
- Love In Bondage (2002)
- Miracle (2002)
- Pretender (2002)
- Unknown Mission (2002)
- Never Come Back (2002)
- Terrible Sin (2001)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Nkiru Sylvanus Bio, Age, Education, Husband, Marriage, Wedding, Career". AfricanMania (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-06-23. Archived from the original on 2019-11-28. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ Haliwud (2016-02-02). "Photos: Veteran Nollywood Actress, Nkiru Sylvanus Flaunts Her New Look". Information Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Veteran Actress, Nkiru Sylvanus Turns Musician, Releases Gospel Album". Within Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-06-07. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ Obioji, Amaka (2018-06-20). "I’ve never been married, looking for a man to marry me now - Actress Nkiru Sylvanus". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "The good, bad and sweet story of Nkiru Sylvanus". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-11-16. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Nse, Nkiru Sylvanus and Ivie Okujaiye battle for AMVCA award tonight!". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-03-07. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ 7.0 7.1 "Gunmen kidnap Nkiru Sylvanus, demand N100m". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-12-16. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Nkiru Sylvanus". IMDb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Celebrities who made headlines in 2018". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-11-28. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Celebrities who made headlines in 2018". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-11-28. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Celebrities that made headlines in 2017 – Part 1". guardian.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-11-28. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Nkiru Sylvanus 'I will act in more movies this year,' actress reveals". www.pulse.ng. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ Orenuga, Adenike. "Nkiru Sylvanus gets new appointment in Imo" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Nkiru Sylvanus gets third political appointment in 3 years". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-09-17. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Actress Nkiru Sylvanus Picks Another Juicy Job In Imo". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-09-17. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Gov. Okorocha's Aide, Nkiru Sylvanus, Kidnapped In Owerri". Sahara Reporters. 2012-12-16. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "THE ABDUCTION OF NKIRU SYLVANUS IN OWERRI". www.thenigerianvoice.com. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Kidnap of Nkiru Sylvanus". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 19.0 19.1 "Jubilation as Nkiru Sylvanus, Okoli regain freedom". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-12-20. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Actress-Cum-Politician, Nkiru Sylvanus Abducted By Gunmen". www.thenigerianvoice.com. Retrieved 2019-11-28.
- ↑ Orenuga, Adenike. "Nkiru Sylvanus weds Oge Okoye’s ex-husband, Stanley Duru" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-28.
- ↑ "Oge Okoye Actress’ ex-husband reportedly marries Nkiru Sylvanus". www.pulse.ng. Retrieved 2019-11-29.
- ↑ Falae, Vivian (2018-05-01). "Oge Okoye's ex-husband story". www.legit.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-29.