Shahan ful, ní ìgékúrú ful, jẹ́ oúnjẹ tí ó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Sudan, South Sudan, Somalia, Ethiopia àti àwọn orílẹ̀-èdè kan ní ilẹ̀ Áfíríkà, èyí tí wọ́n sáábà máa ń jẹ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ àárọ̀. Wọ́n gbà pé oúnjẹ yìí wá láti orílẹ̀-èdè Sudan, wọ́n máa ń sè é nípa rírẹ ẹ̀wà fava díẹ̀ díẹ̀ nínú omi. Nígbà tí ẹ̀wà yìí bá rọ̀ ni wọ́n máa lọ̀ ọ́ kúná. Wọ́n sáábà máa ń jẹ ẹ́ pẹ̀lú àlùbọ́sà, tòmátò, àti ata báwà, pẹ̀lú yogurt, feta cheese, òróró, tesmi, berbere, ẹlẹ́rìndòdò, cumin, àti [[ata]. Ó gbajúmọ̀ nígbà àwẹ̀ Ramadan àti nígbà àwẹ̀ Lent.

Ful
Shahan ful presented alongside olive oil, berbere, various vegetables, and a roll of bread.
Alternative namesFūl
CourseBreakfast, main course
Region or stateSudan, South Sudan, Somalia, Ethiopia and Eritrea
Main ingredientsFava beans, olive oil, cumin
VariationsLemon juice, onion, parsley, garlic, berbere, niter kibbeh
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Oúnjẹ yìí fara jọ ful medames, oúnjẹ kan tí ó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Egypt.[citation needed]

Wò pẹ̀lú

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe

Àdàkọ:Legume dishes Àdàkọ:African cuisine