ONTV Nigeria
ONTV Nigeria jẹ ikanni tẹlifisiọnu ti o wa ni ìpinlè Eko, Nàìjíría .
ONTV je ikanni igbohunsafefe olokiki ní Nigeria, ONTV jẹ ikanni ti o kókó gba àmì-èye ìkànnì igbohunsafefe ti awon ènìyàn n nwo julọ ni ipinle Eko. [1]
Òkïkí won
àtúnṣeLati ọdun 2013, ONTV ti di ikanni igbohunsafefe ti opolopo àwon ilé-isé ibanipolowo oja ma un pe olokiki jùlo, awon ilé-isé ipolowo bi Media perspective. .
ONMAX
àtúnṣeNi ọjọ 11 June ọdun 2015, ONTV ṣe ifilọlẹ lori ikanni DStv 257 ati GoTV Channel 96, won si tẹsiwaju ni síse àwon orisirisi ètò lori Dstv ati bouquet GOtv. [2]
Otún le wo
àtúnṣe- Akojọ ti awọn tẹlifisiọnu ibudo ni Nigeria
- Akojọ ti awọn ikanni iroyin
- Akojọ ti awọn nẹtiwọki tẹlifisiọnu nipasẹ orilẹ-ede
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ Valentine, Shaba (June 21, 2015). "Why ONTV inception has consistently been rated the number one terrestrial station in Lagos’ – ONTV CEO Tajudeen Adepetu". Vnolly Magazine. Archived from the original on June 22, 2015. Retrieved September 19, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Why we launched ONTV Max on DStv platform - Adepetu - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2015-06-26. http://www.vanguardngr.com/2015/06/why-we-launched-ontv-max-on-dstv-platform-adepetu/.