Oba Oluwo Ti Ilu Iwo
Oluwo Ti Ilu Iwo ni oruko oye Oba alade ti o n joba ni ilu Iwo. Iwo je ilu kan ti o gbajumo nile Yoruba ni ipinle Osun ni orile-ede Naijiria.[1] Oba Abdul-Raheed Akanbi Adewale ni oba ti o wa lori oye lowolowo ni ilu Iwo. Oba Adewale Akanbi joba ni odun 2015[2]
Awon Itokasi
- ↑ "Iwo Kingdom". Wikipedia. 2010-09-26. Retrieved 2019-09-18.
- ↑ Eribake, Akintayo (2015-11-12). "How Prince Akanbi emerged new Oluwo". Vanguard News. Retrieved 2019-09-18.