Àdàkọ:More citations needed

Àdàkọ:Sources exist

Odolaye Aremu
Mohammodu Odolaye Aremu
Ọjọ́ìbíIlorin
Ìbẹ̀rẹ̀Ilorin
Irú orinDadakuada
Occupation(s)Folk musician, Praise singer
InstrumentsGangan, Bata Talking Drum
LabelsOlatubosun Records

Mohammodu Odolaye Aremu je omo bibi ilu Ilorin, olorin Dadakuada ti o korin ni opolopo ilu Yoruba ti o si se awo orin pupo sile titi o fi ku lodun 1997. [1] Nigba aye re, o ti gbe ni opolopo agbegbe pẹlu Ibadan, Ilorin, Abeokuta, Okeho, Shaki ati Eko. Sugbon, o lo opolopo akoko re ni ilu Ibadan.

Iṣẹ iṣe orin

àtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ àwọn olórin Yorùbá, ó kọrin ìyìn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn pàtàkì àti olókìkí láwùjọ. Eyi pẹlu Dokita Olusola Saraki, Oloye Alhaji Abdul-Azeez Arisekola Alao ; Alhaji Jimoh Saro, Chief Meredith Adisa Akinloye, Oba Lamidi Adeyemi Olayiwola III, Chief Ladoke Akintola, Ariyibi Adedibu and many others. [2][3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe