Ìran Yorùbá
Kini Yoruba? Tani awon èniyàn Yoruba? Kini edè Yoruba?
àtúnṣe
Ìran Yorùbá, àwọn ọmọ Yorùbá tàbí Ọmọ káàárọ̀-oòjíire, jé árá ìpinle ẹ̀yà, ní apá ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Áfríkà. Wọn jé árá ìpin àwọn ìran to pò ju ní orílẹ̀ Áfríkà. Ilẹ̀ Yorùbá ní púpò nínú wọ́n.[1] Ẹ lè ri wọ́n ní ìpínlẹ̀ púpò bíi ìpínlẹ̀ Ẹdó, Ìpínlẹ̀ Èkìtì, ìpínlẹ̀ Èkó, Ìpínlẹ̀ Kwara, ìpínlẹ̀ Kogí, ìpínlẹ̀ Ògùn, Ìpínlẹ̀ Oǹdó, ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, àti ní ẹ̀yà ila ọ́wọ́ òsi ti ilè Nàìjíríà. Ẹ tún le rí wọ́n ní ìpínlẹ̀ to wa nínú orílẹ̀-èdè Olómìnira Benin (Dahomey), ní orílẹ̀-èdè Sàró (Sierra Leone), àti ní àwọn orílẹ̀-èdè miiran bíi àwọn tí wọ́n pè ní Togo, Brazil, Cuba, Haiti, Amẹ́ríkà ati Venezuela. Àwọn Yorùbá wà l’árá àwọn to tóbí ju ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó le jẹ́ pe àwọn lo
pọ̀ jù, abí kí wọ́n jẹ́ ìkejì, tàbí ẹ̀yà kẹta tí wọ́n pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3]
Àwọn Yorùbá jẹ́ àwọn ènìyàn kan ti èdè wón pín sí orísirísi. Diẹ̀ lára àwọn ìpínsísọ̀rí àwọn èdè wọn ni a ti ri: "Èkìtì"; "Èkó"; "Ìjèbú"; "Ìjẹ̀ṣhà"; "Ìkálẹ̀"; "Ọ̀yọ́"; "Ẹ̀gbá" àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Àwọn ìpínsísọ̀rí yí ni a ń pe ní ẹ̀ka èdè tàbí èdè àdúgbò. Ìran Yorùbá je ènìyàn kan tí wọ́n fẹ́ràn láti máà se áájò àti àlejò àwọn ẹlẹ́yà míràn, wọ́n sì ma ń nífẹ́ sí ọmọ'làkejì.
Èdè
àtúnṣeÈdè Yorùbá jé èdè ti àwọn ìran Yorùbá ma'ń sọ sí ara wọn. Ójẹ́ èdè to pé jù ni ilẹ́ Yorùbá. Ẹ lè ri èdè yi ni Ilẹ Nàìjíríà (Nigeria), Ilẹ Benin, ati ni Ilẹ Togo. Iye to'n sọ èdè yi ju ni gbogbo ilẹ́ Yorùbá 30 milliọnu lọ.[4][5]
Ona asopo ti orisirisi dialects ti èdè Yoruba:
àtúnṣe- https://en.wikipedia.org/wiki/File:A_short_oral_history_of_Egba_in_Egba_Language_by_its_native_speaker.webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_Oral_history_of_Okeho_in_Onko_language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_Oral_history_of_Saki_in_Saki_language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Iwo_in_Iwo_language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Ijan_Ekiti_in_Ijan_Ekiti_Language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Ile_Ife_in_Ile-Ife_language_by_a_native_speaker.webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Ilesha_in_Ijesha_language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:A_short_oral_history_of_Irun_in_Irun_Akoko_dialect_by_native_speaker.webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Owo_in_Owo_language_by_a_native_speaker.webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Idanre_in_Idanre_language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Ijebu_in_Ijebu_language_by_a_native_speaker.webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:Short_oral_history_of_Ikale_in_Ikale_language_by_a_native_speaker_(non-subtitled).webm
- https://en.wikipedia.org/wiki/File:A_short_oral_history_of_Isua_in_Ifira_dialect_by_a_native_speaker.webm
Ohun pataki ni asa ati èdè Yoruba
àtúnṣeNi asa ati èdè Yoruba, òwó se pataki gidigan. Ni asa wa, ti e ba fe ki awon agba tabi awon èniyàn ti o tobi ni odun ju iwo. O nilo lati dobale, e ko le so "bowani" e ma se be o! E nilo lati dọbalẹ. Ni asa wa ati ni èdè wa, òwó se pataki gidigan, ti èniyàn tobi ni odun ju iwo e nilo lati fikun "e" siwaju ohun ti e fe so. "E kaaro," "E pele," "E kúuṣẹ́," sùgbón ti e ba ba àwọn èniyàn soro ti o ni odun kekere ju iwo tabi ti won ni odun ti je kanna pèlú iwo, e ma lo "e" e le n so "kaaro," "pele," ati "kúuṣẹ́."
Se o je otito pé edè Yoruba n fi ku?
àtúnṣeBee ni, o je otito pé ede Yoruba n fi ku? Kini ede fun be? Idi fun iku ede Yoruba je pé awon obi, won ko fe ko awon omodé re ede Yoruba. Opolopo èniyàn ro pé ede Yoruba ko se pataki. Won ro pé ede Yoruba je fun awon otoshi, awon talaka ati awon èniyàn ti ko ni eto-eko (awon láìlẹ́kọ̀ọ́). Sùgbon, o ko je otito, Yoruba ko je fun awon èniyàn ti o ni eto-eko, Yoruba je fun gbogbo èniyàn Yoruba. Awa nilo lati yipada ero inu wa. O ko dara nigba awa n so pé ede Yoruba ko se pataki tabi o je fun awon lailekoo. Opolopo èniyàn bere lati ikorira ede abinibi won dabi Yoruba, Igbo, ati awon miiran. Awa nilo lati mu Yoruba pelu wa, ki i se fi Yoruba ni idoti. Awon Germans won n so German ati inu won dun gidigidi nitori won n so German, awon Chinese won n so Chinese ati inu won dun gidigidi nitori won n so Chinese, awon Russians, won n so Russian ati inu won dun gidigidi nitori won n so Russian sùgbon awon Yoruba, won ko n so Yoruba, ati inu won ko dara nitori won n so Yoruba, ni otito, won n ko fe so Yoruba. Akoko ti dé, awa nilo lati yipada ero inu wa, ko dara. Awon omodé ni Canda, Amerika, China, Jermani, ati awon Dutch, omodé won, won n so ede ti obi won, sùgbon awon omodé wa, won ko so ede wa.
Èdè Yoruba ni ogbon ati orisirisi owe, awa nilo lati soji ede Yoruba, ti awa ko soji ede Yoruba, o ma fi ku patapata, ati awa ko le soji ede Yoruba. Akoko ti de, awa nilo lati se kankan, sugbon o ma fi ku patapata.
Se èdè Yoruba je dandan ni ilè Yoruba?
àtúnṣeYoruba je dandan ni Ìpinlè Èko (Lagos State), ati ni ipinle Osun, sùgbon Yoruba ko je dandan ni ipinle Oyo, Kwara, Ekiti, Ogun, Collines, tabi ni Ondo.
Ko si alaye ti to ni èdè Yoruba
àtúnṣeShe ti mo pé awa ko ni alaye ti to ni ede Yoruba. Idi yii, je okan ninu awon idi ti o ṣojuuṣe si iku ede Yoruba. Awa nilo lati da awon alaye ni ede Yoruba.
Bawo awa le soji èdè Yoruba?
àtúnṣeAwa nilo lati lo Yoruba lori ayelujara, intaneeti (online) awa nilo lati so èdè Yoruba. Ti o ba awa ko le lo Yoruba lori ayelujara, o ma fi ku, nitori ayelujara ti di ona titun lati ibara eni soro.
Se o wa ireti fun ede Yoruba?
àtúnṣeBee ni, o je ireti fun ede Yoruba. She ti mo pé ni Ìpínlẹ̀ Èkó (Lagos State) ati ni ipinle Osun, Yoruba o je dandan fun awon omo ilé-iwé. Ati ni awon ile-ẹkọ giga pato, awon omo ilé-iwé nilo lati mo ede Yoruba fun gbigba. Ati she ti mo pé won ti se itumo fun Twitter ni èdè Yoruba, bee ni, won ti se itumo! Twitter wa je ni èdè Yoruba nissi!
Bawo mo le ko èdè Yoruba?
àtúnṣeE le ko edè Yoruba lori «Memrise»
Se Duolingo je ni èdè Yoruba?
àtúnṣeRara, Duolingo ko wa ni èdè Yoruba sùgbon «Memrise» ni èdè Yoruba.
https://www.memrise.com/en/learn-yoruba
Melo ni èniyàn n so èdè Yoruba?
àtúnṣeegbélégbè aadota (egberun egberun aadota) èniyàn n so èdè Yoruba! (50,000,000)
Se Siri tabi Alexa, se won le so èdè Yoruba?
àtúnṣeRara, Siri ati Alexa, won ko le so èdè Yoruba.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Yoruba People". New World Encyclopedia. 1960-10-01. Retrieved 2023-06-13.
- ↑ "Yoruba - Introduction, Location, Language, Folklore, Religion, Major holidays, Rites of passage". World Culture Encyclopedia. 2007-04-03. Retrieved 2023-06-13.
- ↑ "Yoruba People of Nigeria – Yoruba People History & Culture". Guide to Nigeria tourism, local culture & investments. 2015-09-13. Archived from the original on 2023-05-27. Retrieved 2023-06-13.
- ↑ "Yoruba - people". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2023-06-13.
- ↑ study.com https://study.com/learn/lesson/yoruba-people-language-culture-history-music.html. Retrieved 2023-06-13. Missing or empty
|title=
(help)