Ohùn
Ohùn ènìyàn ni ó jẹ́ ìró kan tí ọmọnìyàn má ń gbé jáde láti inú tán áná ọ̀nà ọ̀fun, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tabí orin, ẹ̀rín, ẹkún ariwo ati ìbòsí (screaming), àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ohùn ènìyàn jẹ́ ohun tí ó jẹ́bàdámọ́ ọmọnìyàn, tí ó níṣe pẹ̀lú ìfúnpọ̀ àti fífẹ̀ kẹ̀lẹ̀ ọ̀fun ènìyàn nígba tí wọ́n bá fẹ́ gbé ìró kan tàbí òmíràn jáde. Lára àwọn irúfẹ́ ìró mìíràn tí ohùn tún lè gbé jáde ni ìfé àti ìsọ-wúyẹ́.[1] [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "About the voice". www.lionsvoiceclinic.umn.edu. Retrieved 2018-02-08.
- ↑ Titze, IR; Mapes, S; Story, B (1994). "Acoustics of the tenor high voice.". The Journal of the Acoustical Society of America 95 (2): 1133–42. Bibcode 1994ASAJ...95.1133T. doi:10.1121/1.408461. PMID 8132903.