Olabiyi Babalola Joseph Yaï (ọjọ́-ìbí 1939[1]) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Benin àti ọ̀jọ̀gbọ́n lítíréṣọ̀ ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Èdè àti Lítíréṣọ̀ Áfíríkà ni Yunifásítí Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (Obafemi Awolowo University) ní ìlú Ifẹ̀, ní orilẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ọdún 1988 ni olùkọ́ yìí fi ẹ̀yìn tì ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí. Yai tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi aṣojú orílẹ̀-èdè Benin sí UNESCO, bẹ́ẹ̀ sì ni ó tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi alága ìgbìmọ̀ apàṣẹ rẹ̀.[2]

Olabiyi Yai