Olaitan Yusuf
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Olaitan Yusuf (tí wọ́n bí ní 12 January 1982) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tó ń gbá eré àgbásíwájú.[3][2][1] Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ Nigeria women's national football team. Ó sì wà lára ẹgbẹ́ tó ṣeré ní 2003 FIFA Women's World Cup.[3]
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kínní 1982[1] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Ilorin, Kwara, Nigeria[1] | ||
Ìga | 1.81 m[2] | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2003–2004 | Pelican Stars | ||
National team‡ | |||
Nigeria | 3 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Olaitan Yusuf Induction Presentation p. 34. claytonstatesports.com. Retrieved 26 December 2019.
- ↑ 2.0 2.1 Olaitan Yusuf – Profile. worldfootball.net. Retrieved 26 December 2019.
- ↑ 3.0 3.1 "FIFA Women's World Cup USA 2003 – Technical Report" (PDF). FIFA Women's World Cup United States 2003. FIFA. 2003. p. 80. Archived from the original (PDF) on 26 December 2011. Retrieved 2007-09-28. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)