Olajumoke Bodunrin
Olajumoke Bodunrin, ( tí wọn bi ní ọjọ́ kèje, oṣù kejì, ọdún 1945) ti gba ìsinmi gẹ́gẹ́ bí i eléré-ìdárayá ti ilẹ̀ Nàìjíríà,[2] Òun ni wọ́n pè ní ''obìrin Africa tí ó yára jùlọ nínú eré-sísá'', nígbà eré-sísá rẹ̀.[3] Olajumoke gba góòlù ní All-Africa Games,1965, ní Brazzaville, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò, kí ó tó lọ ṣojú ilè Nàìjíríà ní Summer Olympics, ti 1968, ní Mẹ́ksíkò.[4]
Òrọ̀ ẹni | |||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kejì 1945 Odo-Asanyin, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà[1] | ||||||||||
Height | 1.52 m (4 ft 12 in) | ||||||||||
Weight | 44 kg (97 lb) | ||||||||||
Sport | |||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Eléré-ìdárayá | ||||||||||
Event(s) | 100 m, 400 m | ||||||||||
Achievements and titles | |||||||||||
Personal best(s) | 100 m – 11.71 (1968) 400 m – 56.1 (1968)[1] | ||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 Olajumoke Bodunrin. Sports Reference
- ↑ "Olajumoke Bodunrin". FanBase. Retrieved 13 September 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "The Death of Nigerian Sports And A Walk Down Memory Lane". Nigerian Muse. 22 August 2009. Retrieved 13 September 2015.
- ↑ "1968 Olympic Games". Sports Bank. Retrieved 13 September 2015.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]