Olamide
Ọlámídé Adédèjì tí a bí ní ọjọ́ Kéẹ̀dógún oṣù Kẹta,ọdún 1989 (15-3-1989), ní agbègbè Bàrígà ní Ìpínlẹ̀ Èkó tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ọlámidé Badoo tàbí BaddoSneh, jẹ́ gbajú gbajà olórin hip-hop, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1][2] Ó jẹ́ olórin hip-hop tí ó ń akọrin pẹ̀lú àmúlù-ma la èdè Yorùbá àti èdè Gẹ̀ẹ́sì. Ní ọdún 2011, ó ṣe àgbéjáde àwo orin kan Rapsodi lẹ́yìn tí ó tọwọ́bọ̀wé Coded Tunes. YBNL, tó jẹ́ orin ẹlẹ́ẹ̀kejìrẹ̀ jáde lábẹ́ ẹgbẹ́ orin rẹ̀ "Yahoo Boy No Laptop" tí a tún mọ̀ sí YBNL Nation. Ní ọjọ́ keje oṣù kọkànlá, ọdún 2013, ó ṣe àgbéjáde àwo orin ẹlẹ́ẹ̀kẹta rẹ̀ Baddest Guy Ever Liveth. Orin àdákọ rẹ̀ "Durosoke" àti "Yemi My Lover" jáde nínú àwo orin náà. Ní ọjọ́ kẹtàdínlógún, oṣù keje, ọdún 2013, Olamide jẹ́ olórinàkọ́kọ́ tó máa tẹwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Cîroc.[3]
Ọlámidé | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Ọlámidé Adédèjì |
Ọjọ́ìbí | 15 Oṣù Kẹta 1989 Bariga, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà |
Irú orin | Hip hop |
Occupation(s) | |
Instruments | Vocals |
Years active | 2011–present |
Labels | YBNL Nation |
Associated acts |
Ìgbésí ayé àti iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́gẹ́ bí akọrin
àtúnṣeA bí Olamide Gbenga Adedeji sí Bariga, Ipinle Èkó,[4] ní ọjọ́ karùndínlógún, oṣù kẹta, ọdún1989. Òun ni ọmọ kejì láàárín àwọn ọmọ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta tí Pa Adedeji àti ìyàwó kejì rẹ̀, Ronke Osisanya Adedeji bí. Olamide ní àbúrò méjì, orúkọ ìkan ń jẹ́ TemmyGold ẹ̀kejì sì ń jẹ́ Eniola Olamilekan (tí a tún mọ̀ sí DJ Enimoney).[5]
Ọlámidé gbé orin tí akọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ ' Ẹni Dúró' jáde lábẹ́ Ilé-iṣẹ́ agbórin jáde Coded Tunes lábẹ́ àkóso ID Cabasa ní ọdún 2010.[6] Ó kẹ́kọ̀ọ́ mass communication ní Tai Solarin University àmọ́ kò kà á gboyè torí owó ìṣúná.[7]
Adedeji fẹ́ abábìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Adebukunmi Aisha Suleiman. Wọ́n sì jọ bímọ méjì, tí orúkọ wọn ń jẹ́ Maximilian Boluwatife àti Tunrepin Myles.[8][9]. Orin "Eni duro" ló gbe Ọlámidé sí ipò gíga láàrín àwọn olórin Hip-hop lóríẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeÀwo orin rẹ̀
àtúnṣe- Rapsodi (2011)
- YBNL (2012)
- Baddest Guy Ever Liveth (2013)
- Street OT (2014)
- Eyan Mayweather (2015)
- The Glory (2016)
- Lagos Nawa (2017)
- Carpe Diem (2020)
- UY Scuti (2021)
- Unruly (TBA)
Àwọn orin àjùmọ̀kọ àti EPs
àtúnṣeÀtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeYear | Event | Prize | Recipient | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2022 | The Headies 2022 | Best Rap Album | Carpe Diem | Gbàá | |
Headies Viewer's Choice | Infinityfeaturing Omah Lay|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Album Of The Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Best Male Artist | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Best Rap Single | Loading featuring Bad Boy Timz|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
2021 | All Africa Music Awards | Song Of The Year | "Infinity" featuring Omah Lay|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [14] | |
Best West African artiste (male) | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Album Of The year | Carpe Diem|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
2021 | Net Honours | Most played Hip Hop song | "Loading" featuring Bad Boy Timz|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [15] | |
Most Searched Musician (male) | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
2020 | Soundcity MVP Awards Festival | Listeners' Choice | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
2018 | The Headies | Best Street-Hop Artiste | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
Best Rap Album | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Artiste of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Song of the Year | Wo|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [16] | ||||
2016 | Nigerian Entertainment Awards (NEAs) | Album of the Year | Eyan Mayweather | Gbàá | [17] |
Rap Act of the Year | Himself | Gbàá | |||
2015 | City People Entertainment Awards | Rap Artist of the Year | Himself | Gbàá | |
The Headies 2015 | Best Street-Hop Artiste | Gbàá | |||
Artiste of The Year | Gbàá | ||||
Best Pop Single | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
TooXclusive Awards 2015 | Certified Banger of The Year | Shakiti Bobo | Gbàá | ||
Video Wonder of The Year | Melo Melo | Gbàá | |||
Artiste of The Year | Himself | Gbàá | |||
Male Artiste of The Year | Himself | Gbàá | |||
Best Street Hop Track | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
'Reggae Blues'
(HarrySong featuring Olamide, KCee, Iyanya & Orezi) |
Wọ́n pèé | ||||
'Ladi'
(Olamide & Phyno featuring Lil Kesh) |
Wọ́n pèé | ||||
Best Hip-Hop Track | 'Local Rappers'
(Reminisce featuring Olamide & Phyno) |
Gbàá | |||
Mixtape of The Year | '2 Kings'
(Olamide & Phyno) |
Gbàá | |||
Album of The Year | Street OT | Gbàá | |||
2014 | The Headies 2014 | Artiste of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
Best Rap Album | Baddest Guy Ever Liveth | Gbàá | |||
Album of the Year | Gbàá | ||||
Best Rap Single | "Dope Money"
(featuring Phyno) |
Wọ́n pèé | |||
2014 Channel O Music Video Awards | Most Gifted West | "Turn Up" | Gbàá | [18] | |
2014 Nigeria Entertainment Awards | Best Rap Act of the Year | Himself|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [19] | ||
MTV Africa Music Awards 2014 | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [20] | |||
City People Entertainment Awards | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [21] | |||
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||||
Most Popular Song of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Rap Album of the Year | Baddest Guy Ever Liveth|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
World Music Awards | World's Best Male Artist | Himself|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [22] | ||
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||||
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||||
2013 | Nigeria Music Video Awards | Video of the Year | "Durosoke"|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [23] | |
Best Afro Hip Hop Video | Gbàá | ||||
The Headies 2013 | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [24] | |||
Best Street Hip-Hop Artiste | Gbàá | ||||
Best Rap Single|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||||
"Ghost Mode"
(Phyno featuring Olamide) |
Wọ́n pèé | ||||
Artiste of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Lyricist on the Roll | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Best Rap Album | YBNL | Gbàá | |||
Album of the Year | Gbàá | ||||
2013 Nigeria Entertainment Awards | Best Album of the Year | Gbàá | [25] | ||
Best Rap Act of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [26] | |||
Music Video of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Best Indigenous Artiste | Himself | Gbàá | [25] | ||
Best Collabo | "Ghost Mode"
(Phyno featuring Olamide) |
Gbàá | |||
2012 | The Headies 2012 | Hip Hop World Revelation of the Year | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | [27] | |
Best Rap Single | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
Best Rap Album | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
2011 | The Headies 2011 | Next Rated | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ liano (2019-09-01). "Olamide's New Song "Pawon" is a party starter". 9jabaz. Archived from the original on 2019-09-01. Retrieved 2019-09-01.
- ↑ "Olamide's Biography". Biography Home: Olamide Personal Data. Retrieved 8 January 2014.
- ↑ Abimboye, Micheal (13 July 2013). "Checkout Top Three Artiste That Run And Rule The Nigerian Music Industries". Premium Times. Archived from the original on 16 June 2018. Retrieved 19 April 2018.
- ↑ Oloworekende, Wale (2021-06-16). "Nigerian rapper Olamide: ‘People have a very limited understanding of the ghetto’". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-27.
- ↑ "I was sleeping when I heard about my mother’s death – DJ Enimoney". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-25. Retrieved 2021-11-20.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedOlamide Personal Data2
- ↑ "Why I dropped out of school – Olamide". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-08-26. Archived from the original on 2021-11-20. Retrieved 2021-11-20.
- ↑ "Nigerian rapper, Olamide welcomes 2nd child with fiancee in US – P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-11-20.
- ↑ "Maria Okanrende Drags Out Olamide". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-11. Retrieved 2021-11-20. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "2 Kings (album)", Wikipedia (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), 2021-01-09, retrieved 2022-10-19
- ↑ "Olamide "999" EP Album". Pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ Ranger, Lone (2020-02-11). "Olamide – 999 (EP) (Full Album)". DCLeakers.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-19.
- ↑ airwavesnaija (2013-12-13). "(Music) Jahborne – Badder Dan Dem ft Olamide". AIRWAVES NAIJA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-19.
- ↑ "Afrima 2021 – The Class of 2021". Afrima (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-10-02. Retrieved 2022-10-21.
- ↑ "Net Honours – The Class of 2021". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-07.
- ↑ Ohunyon, Ehis. "Wizkid, Davido, Simi and Mayorkun are among the big winners at the 12th edition of the Headies Music Awards.". Archived from the original on 2019-08-16. https://web.archive.org/web/20190816110833/https://stemarsblog.com/music/.
- ↑ "NEA 2016: Adekunle Gold, Olamide, Kiss Daniel, others win big". PulseNg. 6 September 2016. Archived from the original on 25 July 2017. Retrieved 14 November 2016.
- ↑ Marshall, Rhodé (5 September 2014). "Channel O Africa announces Music Video Awards nominees". Mail & Guardian. Retrieved 12 September 2014.
- ↑ Abimboye, Micheal (31 May 2014). "Pop duo, Skuki, reject Nigerian Entertainment Awards nomination". Premium Times. Retrieved 1 June 2014.
- ↑ "Mafikizolo, Uhuru, Davido lead nominations for MTV Africa Music Awards". Sowetan LIVE. Retrieved 17 April 2014.
- ↑ Jasanya, Olamide (24 June 2014). "Who won what at City People Entertainment Awards 2014". Nigerian Entertainment Today. Archived from the original on 28 June 2014. Retrieved 29 July 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "D’banj, Tuface, Jay-Z, Kanye West, Davido, Kcee Nominated at World Music Awards". Channelstv.com. 20 February 2014. Retrieved 17 April 2014.
- ↑ "Flavour is biggest winner at Nigerian Music Video Awards 2013". Nigerian Entertainment Today. 16 November 2013. Archived from the original on 14 June 2014. Retrieved 25 February 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Olamide Heads The Headies". Thisday. 29 December 2013. Archived from the original on 22 February 2014. Retrieved 19 March 2014.
- ↑ 25.0 25.1 Alonge, Osagie (3 September 2013). "Olamide emerges biggest winner at NEA 2013 [Full Winners List]". Nigeria Entertainment Today. Archived from the original on 1 July 2014. Retrieved 20 August 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Abimboye, Micheal (31 May 2013). "Nigerian Entertainment Award announces 2013 nominees". Premium Times. Retrieved 20 August 2014.
- ↑ Elebe, Dami (29 August 2012). "Headies Awards 2012". Connectnigeria.com. Archived from the original on 31 December 2013. Retrieved 19 March 2014.