Olasope O. Oyelaran
Olasope O. Oyelaran jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ ẹ̀dá-èdè[1] ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti lítíréṣọ̀ Áfíríkà ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀, ní Ilé-Ifẹ̀. Láti ìgbà tí wọ́n ti dá ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ yìí sílẹ̀ ní ọdún 1975 ó ti wà ní ibẹ̀. Kí ó tó di àsìko ̀ yí, ó ti ń ṣiṣẹ́ ní Institute of African Studies, OAU, Ifẹ̀ láti ọdún 1970. Òun ni olùkọ́ àkọ́kọ́ ní ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ èdè àti Lítíréṣọ̀ Afirika, OAU. Ó fẹ̀yìn tì lẹ́nu iṣẹ́ olùkọ́ni ní ọdún 1988.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "African Books Collective: Olasope O. Oyelaran". African Books Collective. Retrieved 2021-07-26.
- ↑ "Olasope O Oyelaran books and biography". Waterstones. Retrieved 2021-07-26.