Olatunde Farombi jé ọ̀jọ̀gbọ́n ìmọ̀ Biochemistry àti Molecular toxicology. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Royal Society of Chemistry (FRSC) ni orile ede UK, àti Nigerian Academy of Science. Ó sì tún jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ African Academy of Sciences at Academy of Toxicological Sciences. Ó gboyè ọ̀mọ̀wé nínú ìmọ̀ Biochemistry láti ilé ẹ̀kọ́ gíga, ìyẹn Yunifásítì ìlú Ìbàdàn.[1]

Ó jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú àwọn onímọ̀ Toxicology ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[2] Ise iwadi Ojogbon Olatunde Farombi fun bi odun marun-dinlogbon da lori imo nipa Molecular Toxicology, Cellular Oxidative Stress Mechanisms Reproductive and Environmental Toxicology.[3]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The AAS". Farombi Ebenezer. Archived from the original on 2023-01-26. Retrieved 2023-02-03. 
  2. Osinusi, Femi (2021-03-19). "Gureje, Farombi, others make list of top world scientists". Tribune Online. Retrieved 2023-02-03. 
  3. "The AAS". Farombi Ebenezer. Retrieved 2024-12-11.