Oleta Adams
Oleta Adams (ojoibi May 4, 1953) jẹ̀ akọrin ẹ̀mí àti àti atẹdùùrù ará Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún agbára ohùn rẹ̀.
Oleta Adams | |
---|---|
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Oleta Angela Adams |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kàrún 1953 Seattle, Washington, U.S. |
Irú orin | Gospel, soul[1] |
Occupation(s) | Singer |
Instruments | Vocals, piano |
Years active | 1980–present |
Labels | |
Associated acts | Tears for Fears, Mervyn Warren, Brooklyn Tabernacle Choir |
Website | oletaadams.com |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayẹ́ rẹ̀
àtúnṣeAdams tí wón bí gẹ́gẹ́ bí ọmọbìnrin si ajíhìnrere, ti o si dàgbà sí gbígbọ́ orin ẹ̀mí. Nígbà tí o dàgbà, awọn ẹbí rẹ̀ kólọ sí Yakima, Washington. Ó bẹ̀rē orin kíkọ ni sọ́ọ́sì.
Kí ó tó rí ànfàní láti kọ orin rẹ, Adams fojú winá ọ̀pọ̀lọpọ̀ kíkọ̀sílẹ̀. Ni ọdún 1970s, ó ko lọ si Los Angeles, California, níbi tí o ti o se rẹ́kọ́dù.
Pẹ̀lú àmọ̀ràn olùkọ́ rẹ, Lee Farrell, o kó lọ si Kansas City, Missouri, níbi tí o tí se awọn oríṣiríṣi kikọ orin ni ibi ipejopo.
Ìgbésí ayé rẹ
àtúnṣeNí ọdún 1994, Adams fẹ́ ònílù tí orúko rè njé John Cushon ni Methodist church ti o wa ni Kansas. Wọ́n pàdé ní ọdún 1980 nígbà tí wón jo n se rẹ́kọ́dù fun Adams.[2]
Awards and nominations
àtúnṣeYear | Result | Award | Category | Work |
---|---|---|---|---|
1991 | Nominated | Soul Train Music Award | Best R&B/Urban Contemporary New Artist | —
|
1992 | Nominated | Grammy Awards | Best Female Pop Vocal Performance | "Get Here"
|
1993 | Nominated | Grammy Awards | Best Female R&B Vocal Performance | "Don't Let The Sun Go Down On Me"
|
1994 | Nominated | Soul Train Music Award[3] | Best R&B Single, Female | "I Just Had to Hear Your Voice"
|
1997 | Nominated | Grammy Awards | Best R&B Album | Moving On
|
1998 | Nominated | Grammy Awards | Best Contemporary Soul Gospel Album | Come Walk with Me
|
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Cooper, William. "Oleta Adams". AllMusic. Retrieved March 12, 2018.
- ↑ Norment, Lynn (1996). "Moving on and up with Oleta Adams: with new husband and renewed religious faith, soulful singer scores with new album". Ebony. http://findarticles.com/p/articles/mi_m1077/is_n10_v51/ai_18544356.
- ↑ "Jet". Johnson Publishing Company. 14 March 1994 – via Google Books.