Adeleke Mamora

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Olorunnimbe Mamora)

Adeleke Olurunnimbe Mamora tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kejì ọdún 1953 (16 February 1953) jẹ́ gbajúmọ̀ olóṣèlú àti Mínísítà kékeré fún ètò ìlera lọ́wọ́lọ́wọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti fi ìgbà kan jẹ́ Agbẹnusọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí Ìpínlẹ̀ Èkó lọ́dún 1999, bẹ́ẹ̀ náà wọ́n dìbò yàn án gẹ́gẹ́ bí Sẹ́nétọ̀ lọ́dún 2007, láti ṣojú lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress. [1] [1]In 2003 he was appointed chairman of the Senate Committee on Ethics, Privileges and Public Petitions.[2] [3]

Adeleke Olurunnimbe Mamora
Minister of State for Health
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
23 August 2019
Speaker of the 4th Lagos State House of Assembly
In office
2 June 1999 – 30 May 2003
DeputyAdetoun Adediran
AsíwájúShakirudeen Kinyomi
Arọ́pòJokotola Pelumi
Senator for Lagos East
In office
29 May 2007 – 6 June 2011
AsíwájúAdeseye Ogunlewe
Arọ́pòGbenga Bareehu Ashafa
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kejì 1953 (1953-02-16) (ọmọ ọdún 71)
Lagos State, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Sen. Adeleke Olurunnimbe Mamora". National Assembly of Nigeria. Archived from the original on 2016-03-03. Retrieved 2010-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. SEBASTINE HON (2003-10-14). "Senate Bribery Allegations: Who Lied?". ThisDay. Archived from the original on 2005-11-25. Retrieved 2010-06-14.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "An Improved Senate, But Some Uninspiring Senators...". ThisDay. 24 May 2009. Retrieved 2010-06-14.