Olufunmilayo Olopade

Oníṣègùn

Olufunmilayo I. Olopade, O.O.N.[1](tí a bí ní ọdún 1957 ní orílẹ̀-èdè Naijiria) jẹ́ oníṣègùn tó ní ṣe pẹ̀lú kíkọ́ nípa ẹ̀jẹ̀ súsú, òun sì ni Associate Dean fún Global Health and Walter L. Palmer Distinguished Service Professor nínú ọ̀rọ̀ ìṣègún àti elétò ìlera ní Yúnifásitì ti Chicago.[2][3] Ó tún ń ṣiṣẹ́ bíi olùdarí ti Yunifásítìl ti Chicago Hospital's Cancer Risk Clinic.[4]

Olufunmilayo Olopade
Olopade in 2012
Ọjọ́ìbí1957 (ọmọ ọdún 66–67)
Nigeria
Orílẹ̀-èdèAmerican
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan
Olólùfẹ́Christopher Sola Olopade
Àwọn ọmọDayo Olopade
Àdàkọ:Infobox medical details

Life àtúnṣe

Orílè-èdè Naijiria ni a bí Olufunmilayo Olopade sí, ní ọdún 1957, òun sì ni ọmọ karùn-un láàárín ọmọ mẹ́fà tí àwọn òbí rè bí. Ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti St Anne ní ìlú Ìbàdàn ni ó lọ fún ẹ̀kọ́ girama rẹ̀. Olopade kọ́kọ́ ni lọ́kàn láti di oníṣègùn láti ìgbà èwe rẹ̀ wá nítorí àwọn dọ́kítà àti èròjà fún iṣẹ́ ìwòsàn ṣọ̀wọ́n ní àwọn ìlú ìbílẹ̀ ní Nàìjíríà nígbà náà.[5]

Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè láti University of Ibadan, ní Nàìjíríà, pẹ̀lú MBBS, ní ọdún 1980.[6]

Ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú the Breast Cancer Research Foundation[7] ó sì ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ lórí ipa tí BRCA1 àti BRCA2 ń kó nínú ìdènà àrùn jẹjẹrẹ nínú Ọmú láàárín àwọn obìnrin ilẹ̀ adúláwọ̀.[8][9]

Ó jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́ the American Association for Cancer Research,[10] the American College of Physicians, the Nigerian Medical Association, American Philosophical Society,[11] àti ti Institute of Medicine.[12][13]

Àtòjọ àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ àtúnṣe

  • 1975: Nigerian Federal Government Merit Award[14]
  • 1978: Nigerian Medical Association Award for Excellence in Pediatrics[15]
  • 1980: Nigerian Medical Association Award for Excellence in Medicine [16]
  • 1990: Ellen Ruth Lebow Fellowship[17]
  • 1991: American Society for Clinical Oncology Young Investigator Award [15]
  • 1992: James S. McDonnell Foundation Scholar Award [15]
  • 2000:Doris Duke Distinguished Clinical Scientist Award [18]
  • 2003: Phenomenal Woman Award for work within the African-American Community [15]
  • 2005: Access Community Network's Heroes in Healthcare Award [15]
  • 2005 MacArthur Fellows Program[19]
  • 2015: Four Freedoms Award
  • 2017: Villanova University Mendel Medal
  • On Saturday, May 18, 2019, The Lincoln Academy of Illinois granted Olopade the Order of Lincoln award, the highest honor bestowed by the State of Illinois.[20]
  • 2021: Member of the U. S. National Academy of Sciences.[21]

Olufunmilayo Olopade jẹ́ ọ̀kan lára àwọn African-American mẹ́ta tó rí àmì-ẹ̀yẹ $500,000 gbà. John D. àti Catherine T. MacArthur Foundation ló yan àmì-ẹ̀yẹ yìí. Ẹ̀bùn yìí tó kò nídìí mìíràn nínú ni wọ́n fún Olopade láti rà án lọ́wọ́ fún ọdún márùn-ún, wọ́n sì pè é ní àmì-ẹ̀yẹ ti olóye púpọ̀.[22]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Olufunmilayo I. Olopade, M.D., F.A.C.P., O.O.N. | Office of Research". www.vumc.org. Retrieved 2022-05-25. 
  2. "Olufunmilayo I. Olopade, MD, FACP". The University of Chicago Medicine. Retrieved July 26, 2013. 
  3. "Olufunmilayo Olopade, Ph.D. Research & Selected Publications". The University of Chicago Biological Sciences; Department of Human Genetics. Archived from the original on September 27, 2010. Retrieved July 27, 2013. 
  4. "Dr. Olufunmilayo Olopade: Closing Disparities Through Genetic Testing | Leading Discoveries Magazine" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-06-25. Retrieved 2022-08-10. 
  5. "Olopade, Olufunmilayo Falusi | Encyclopedia.com". www.encyclopedia.com. Retrieved 2020-05-29. 
  6. "Olufunmilayo Olopade | Committee on Cancer Biology". cancerbio.uchicago.edu. Retrieved 2020-05-29. 
  7. "Olufunmilayo Olopade, MD, FACP :: Profile". The Breast Cancer Research Foundation. Retrieved July 26, 2013. 
  8. "Dr. Olufunmilayo Olopade Receives ASCO ACS Award for Pioneering Research in Breast Cancer Genetics". American Society of Clinical Oncology. Archived from the original on July 5, 2013. Retrieved June 26, 2013. 
  9. Scudellari, Megan (August 1, 2013). "Cancer Knows No Borders" (in en). The Scientist. http://www.the-scientist.com/?articles.view/articleNo/36681/title/Cancer-Knows-No-Borders/. 
  10. "Olufunmilayo I. Olopade". AACR. American Association for Cancer Research. 2001. Archived from the original on September 29, 2013. Retrieved June 6, 2013.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. "APS Member History". search.amphilsoc.org. Retrieved 2021-04-02. 
  12. "Directory: IOM Member - Olufunmilayo F. Olopade, M.D., FACP, OON". Institute of Medicine. Retrieved June 28, 2013. 
  13. Easton, John (2 March 2011). "President Obama names Olopade to National Cancer Advisory Board". The University of Chicago News. https://news.uchicago.edu/article/2011/03/02/president-obama-names-olopade-national-cancer-advisory-board. 
  14. Abbah, Theophilus (2012-09-16). "You can't ignore these 10 awardees of national honours". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-06-07. Retrieved 2020-05-29. 
  15. 15.0 15.1 15.2 15.3 15.4 Admin (2019-02-21). "OLOPEDE, Prof (Mrs) Olufunmilayo". Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-25. 
  16. "Olufunmilayo I. Olopade, MD". American Association for Cancer Research (AACR) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-08-10. 
  17. "Dr. Olufunmilayo I. Olopade – H3Africa" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-25. 
  18. "Dr. Olufunmilayo I. Olopade – H3Africa". h3africa.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-05-25. 
  19. "MacArthur Fellows Program:Olufunmilayo Olopade". MacArthur foundation. September 1, 2005. Retrieved July 27, 2013. 
  20. "2019 Laureates Announced by Gov. Rauner". The Lincoln Academy of Illinois (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-08-27. Retrieved 2019-08-27. 
  21. "News from the National Academy of Sciences". April 26, 2021. Retrieved July 5, 2021. Newly elected members and their affiliations at the time of election are: … Olopade, Olufunmilayo F.; Walter L. Palmer Distinguished Service Professor of Medicine and Human Genetics, department of medicine, and director, Center for Clinical Genetics and Global Health, University of Chicago, Chicago , entry in member directory:"Member Directory". National Academy of Sciences. Retrieved July 5, 2021. 
  22. "MacArthur Fellows". MacArthur Foundation. Retrieved January 2, 2022.