Oluremi Oyo
Oluremi Oyo (bíi ni ọjọ́ kejìlá oṣù kẹwàá ọdún1962, o kú ní ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 2014) jẹ́ ogbontarigi oníróyìn àti adarí tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ àwọn oniroyin ni Nàìjíríà. Òun ni oluranlọwọ pàtàkì fún olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ọdún 2003, Olusegun Obasanjo lórí àwọn ọ̀rọ̀ ìkéde, òun sì ni obìnrin àkọ́kọ́ tí ó má de ipò naa.[1][2]
Oluremi Oyo | |
---|---|
Managing Director of the News Agency of Nigeria | |
In office July 2007 – 2013 | |
Arọ́pò | Ima Niboro |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 12 October 1952 Ilorin Kwara State Nigeria |
Aláìsí | 1 October 2014 United Kingdom | (ọmọ ọdún 61)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Non-Partisan |
Iṣẹ́
àtúnṣeO lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos níbi tí ó tí gboyè nínú èrọ ibaraenisọrọ àti ìròyìn.[3] O gboyè masters nínú International relations ni ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Kent ni orílẹ̀ èdè United Kingdom.[4] Oluremi bẹẹrẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oniroyin ni ọdún 1973 ni Nigerian Broadcasting Corporation tí ó ti wà yí orúkọ padà sii Federal Radio Corporation of Nigeria (FRCN). Ó darapọ̀ mọ́ NAN ni 1981 gẹ́gẹ́ bíi alatunse ìròyìn, ó sì kúrò ní ọdún 1985. Ó ti si ṣé fún Inter Press Service News Agency àti International news agency. Ní ọdún 1998, Gen. Abdulsalami Abubakar fi ṣe ìkan laarin awon ti o se ofin fún Nàìjíríà. Ó di oluranlọwọ pàtàkì àgbà fún Olusegun Obasanjo ni ọdún 2003 ló rí ọ̀rọ̀ ìkéde. Ó di adarí fún ẹgbẹ́ àwọn oniroyin tí Nàìjíríà ni oṣù keje ọdún 2007.[5][6][7][8] Ó kú ní orílẹ̀ èdè United Kingdom ni ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá ọdún 2014. Àrùn jẹjẹrẹ ni ó pá.[9][10][11] Wọn sín sí itẹ̀ àwọn òkú ní Yaba ni ìpínlè Èkó.[12] O gba Ẹ̀bùn láti National Council of Catholic Women Organisation of Nigeria merit award[13] àti national award of Officer of the Order of Niger, OON, ni odun 2006. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Nigerian Guild of Editors (NGE), Nigerian Institute of Management (NIM), Nigerian Institute of Public Administrators àti Nigerian Guild of Editors.[14][15]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Former Managing Director of NAN, Oluremi Oyo Is Dead ‹ International Centre for Investigative Reporting". Retrieved 4 October 2014.
- ↑ siteadmin (2014-10-02). "Former President Obasanjo’s spokesperson, Remi Oyo, Dies At 62 | Sahara Reporters". Sahara Reporters. http://saharareporters.com/2014/10/02/former-president-obasanjo%E2%80%99s-spokesperson-remi-oyo-dies-62.
- ↑ "Jonathan, Obasanjo, Mark, others extol Remi Oyo's Virtues, Mourn her". Thisday. Archived from the original on 2015-04-11. https://web.archive.org/web/20150411002934/http://www.thisdaylive.com/articles/jonathan-obasanjo-mark-others-extol-remi-oyo-s-virtues-mourn-her-passing/190453/.
- ↑ "Former President Obasanjo’s spokesperson, Remi Oyo, Dies At 62". Sahara Reporters. October 2, 2014.
- ↑ "IRIN Africa - LIBERIA-SIERRA LEONE: Interpol warrant for Taylor illegal, says defence lawyer - Liberia - Sierra Leone - Conflict". IRINnews. Retrieved 4 October 2014.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "BBC NEWS - Africa - Nigeria rules out Taylor arrest". http://news.bbc.co.uk/1/hi/world/africa/3293613.stm. Retrieved 4 October 2014.
- ↑ "Mum was the force that held us together – Oluremi Oyo’s son".
- ↑ "Oluremi Oyo, former News Agency of Nigeria boss dies - Premium Times Nigeria". October 2, 2014.
- ↑ "Remi Oyo is dead". The Sun. October 3, 2014. http://www.sunnewsonline.com/new/?p=84406m. Retrieved November 14, 2014.
- ↑ "My last moment with Remi Oyo in UK hospital – Nephew :: The Nation". Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 4 October 2014.
- ↑ "President Jonathan Mourns Ex-Nan Boss, Remi Oyo". Archived from the original on 6 October 2014. Retrieved 4 October 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Tears, tributes as Remi Oyo is buried in Lagos". The Sun. October 25, 2014. Retrieved November 14, 2014.
- ↑ "Former Obasanjo's Media Aide, Oluremi Oyo Dies Of Cancer In UK". African Examiner. 2 October 2014. Retrieved 22 May 2020.
- ↑ "Remi Oyo’s Death: Another blow to the Media – IPC – Nigerian Democratic Report".
- ↑ "Mrs. Oluremi Oyo".