Olusoji Fasuba

(Àtúnjúwe láti Olusoji fasuba)

Olusoji Adetokunbo Fasuba ti a bi ni 9 July 1984 je elere ori paapa ologorunibuso.[1] O gbe gba oroke laarin awon elere ile adulawo ni iseju aaya 9.85 titi ti Akanni Simbine Fi gba Ipo naa ni July 2021 pelu iseju aaya 9.84.[2]

Olusoji Fasuba
Olusoji Fasuba in 2007
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ọjọ́ìbí9 Oṣù Keje 1984 (1984-07-09) (ọmọ ọdún 40)
Height175 cm (5 ft 9 in)
Weight70 kg (154 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáRunning
Achievements and titles
Personal best(s)100m: 9.85
200m: 20.52

Iberepepe aye re

àtúnṣe

Wọ́n bí Fasuba sí Sapele, ní Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, ní orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni àkọ́bih nínú ọmọ mẹ́ta. Eré-ìahrayá ti wà nínú ìdílé náà. Ìyá rẹ̀ tó jẹ́ Jamaican, máa ń sáré nígbà tó wà ní ṣàngó òde, òun sì ni àbúrò Don Quarrie, tó jẹ́ gbajúgbajà eléré ìdárayá. Àwọn òbí rẹ̀ fun ní àtìlẹ́yìn láti sá́ré lásìkò èwe rẹ̀, ó sì mọ eré sá gan-an débi pé kò sí ẹni tó le là á ní ilé-ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀. Pàápàá jù lọ, ó mọ bọ́ọ̀lù àfẹ́sẹ̀gbà, football, volleyball àti basketball. Ó sì gba àmì-ẹ̀yẹ láti lọ sí Mixed Secondary School látàri ìwé ọ̀fé tó fún un. Ó máa ń gbé igbá orókè ní gbogbo ìdíje tí wọ́n bá ṣe.[3] Fasuba tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó lọ sí Obafemi Awolowo UniversityIle-Ife, àmọ́ iṣé náà nira fún un. Pẹ̀lú ìgbìyànjú láti ọ̀dọ̀ ìyá rẹ̀, ó fi iṣé ilé-ìwé sílẹ̀, ó sì lọ sí inú eré-ìdárayá lójú pálí[4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Athlete biography: Olusoji Fasuba". Beijing2008.cn. The Beijing Organizing Committee for the Games of the XXIX Olympiad. Archived from the original on 2008-09-12. Retrieved 26 August 2008.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Vazel, P-J (2006-05-16). Take nothing for granted Asafa and Justin, Olu Fasuba has hit the big time!. IAAF. Retrieved on 2010-03-20.
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Resume
  4. Carole Fuchs and Dare Esan (2008-08-03). Focus on Athletes - Olusoji Fasuba. IAAF. Retrieved on 2009-04-16.