Oluwatoyin Temitayo Ogundipe (ọjọ́ìbí 31 May 1960) jẹ́ ọmọ ilé-ìwé Nàìjíríà àti òjògbón nípa imọ-ògbìn. Ọ ṣíṣẹ́ bí ìgbákejì kejìlá (12th) tí Yunifásítì ìlú Èkó láti Oṣù kọkànlá ọdún 2017 sí Oṣù kọkànlá ọdún 2022.[1]

Oluwatoyin Ogundipe
Ìgbákejì kejìlá tí Yunifásítì ìlú Èkó
In office
12 November 2017 – 12 November 2022
DeputyÒjògbón L. O. Chukwu
Òjògbón Ayodele Atsenuwa
Òjògbón Bolanle Olufunmilayo Obo
AsíwájúRahmon Ade Bello
Arọ́pòFolasade Ogunsola
Ìgbákejì Alàkóso (academic research), Yunifásítì ìlú Èkó
In office
6 April 2016 – 12 November 2017
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Oluwatoyin Temitayo Ogundipe

31 Oṣù Kàrún 1960 (1960-05-31) (ọmọ ọdún 64)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́Oluwaseun Ogundipe
Àwọn ọmọ3
Alma materObafemi Awolowo University

Ìgbésí ayé ìbẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Ọjọ́ kokanlelógbón oṣù karùn-ún ọdún 1960 ní wọ́n bí Ogundipe. Fásítì Ifẹ̀ (bayi Obafemi Awolowo University) lọ tí gba oyè Bachelor of Science (B.Sc.) ní Botany. Ọ gbọyè oyè nípa ìmọ ẹ̀kọ́ botany láti Fásítì Ifẹ̀ àti oyè dókítà (Ph.D) láti ilé ìwé gígá kan náà. Lẹhìnna ọ gba oyè Masters ní Ìṣàkóso Ìṣòwò láti Ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ìlú Èkó.[2]

Iṣẹ́

àtúnṣe

Ogundipe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ẹ̀kọ́ rẹ́ ní Yunifásítì tí Èkó gẹ́gẹ́bí olùkọ níbití ọ tí dí ipò òjògbón tí Botany ní 2002. Ọ jẹ́ Dean, School of Postgraduate Studies láti August 2007 sí July 2011 àti Olùdarí, Academic Planning Unit láti Kẹ́rín 2012 sí Oṣù Kẹ́rín ọdún 2016.[3][4]

Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí igbákejì fásítì tí Èkó ní oṣù kọkànlá ọdún 2017.[4] Títí dí ìpinnu láti pàdé rẹ̀ ní Oṣù kọkànlá, ọ jẹ́ ìgbákejì alàkóso Yunifásítì tí Èkó.[4][5]

Wọ́n yọ Ogundipẹ kúrò gẹ́gẹ́ bí igbákejì ọ̀gá àgbà fásítì tí Èkó látọwọ́ ìgbìmọ̀ olùṣàkóso fásítì náà lẹ́yìn ẹ̀sùn àìtọ́ sí owó àti ìwàkiwà tó burú jáì.[6] Bí ọ tí wù kí ọ rí, Ààrẹ Muhammadu Buhari dá a pàdà sípò lórí ìmọràn ìgbìmọ̀ ìwádìí kán tí ọ ríi pé yiyọ́kúrò náà kọ ṣẹ́ pẹ̀lú ìlànà tó tọ.[7][8]

Ìgbésí ayé àrà ẹni

àtúnṣe

Ogundipe tí ní ìyàwó pẹ̀lú ọmọ mẹ́ta.[9]

Àwọ́n ìtọkásí

àtúnṣe
  1. Wahab, Adesina (2022-11-12). "UNILAG VC: Ogundipe out, Ogunsola in". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 1 June 2023. 
  2. Ileyemi, Mariam (10 November 2022). "Sanwo Olu, others hail outgoing UNILAG VC" (in en). www.premiumtimesng.com. https://www.premiumtimesng.com/regional/ssouth-west/564674-sanwo-olu-others-hail-outgoing-unilag-vc.html?tztc=1. 
  3. "UNILAG appoints Prof. Ogundipe new VC | The Sun News". sunnewsonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 4 March 2018. 
  4. 4.0 4.1 4.2 "UNILAG Council appoints Professor Ołuwatoyin Ogundipe as 12th Vice-Chancellor - Vanguard News". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 October 2017. Retrieved 4 March 2018. 
  5. "UNILAG council appoints Prof Oluwatoyin Ogundipe new VC - Daily Post Nigeria" (in en). Daily Post Nigeria. 28 October 2017. http://dailypost.ng/2017/10/28/unilag-council-appoints-prof-oluwatoyin-ogundipe-new-vc/. 
  6. "UNILAG governing council removes Ogundipe as Vice-Chancellor | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-12. Retrieved 2021-02-06. 
  7. Ukpe, William (2020-11-12). "Professor Oluwatoyin Ogundipe reinstated as UNILAG VC by President Buhari". Nairametrics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-06. 
  8. Salaudeen, Omoniyi (15 November 2020). "Prof Oluwatoyin Ogundipe: A long walk to justice". Archived from the original on 18 September 2024. https://web.archive.org/web/20240918082023/https://thesun.ng/prof-oluwatoyin-ogundipe-a-long-walk-to-justice/?amp. 
  9. "PROF. TOYIN OGUNDIPE: NIGERIA'S UNSUNG, TESTED AND TRUSTED ADMINISTRATOR". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-07. Retrieved 2021-02-06.