Àwọn ẹ̀yà ìgbò

(Àtúnjúwe láti Omo Igbo)

Àwọn ẹ̀yà Ìgbò (English /ˈb/ EE-boh,[2][3] also US /ˈɪɡb/;[4][5] tí wọ́n tún ń pè níYíbà[6][7] [8][9] tàbí Heebo;[10] tí àpèjẹ́ wọn ń jẹ́ Ṇ́dị́ Ìgbò Àdàkọ:IPA-ig) ni wọ́n jẹ́ àkójọ pọ̀ àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ní àrin gbùngbùn ìlà Oòrun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Kò sí ẹni tó mọ pàtó ibi tí àwọn ẹ̀yà yí ti wá ṣáájú kí wọ́n tó kóra jọ sí ìletò tí wọ́n wà lóní.[11] Ilẹ̀ Ìgbò pín sí ọ̀nà méjì, àkọ́kọ́ èyí tí ó wà ní apá àríwá tí ó wà ní apá Odò Ọya tó jẹ́ èyí tó tobi jù ti ẹ̀ẹ̀kejì apá ìlà Oòrun. [12][13] Àwọn ẹ̀yà ìgbà Ìgbò jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀yà tí ó pọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ Adúláwọ̀.[14]

Igbo people
File:Igbo_Community_in_Nigeria_and_Africa.svg
Ibùdó ilẹ̀  the Igbo homeland  (dark green)

Nigeria  (green)

Àpapọ̀ iye oníbùgbé
c. 45 million (2020 est.)
Regions with significant populations
Nàìjíríà Nàìjíríà 35.5 million (2020)[1]
Èdè
Ẹ̀sìn

Primarily Christianity, sometimes syncretised with indigenous Igbo religion and belief systems,

Ẹ̀yà abínibí bíbátan

Ibibio, Efik, Annang, Ogoni, Idoma, Igala, Urhobo, Ijaw, Ogoja; more remotely the YEAI group within Volta-Niger

Omo igbo to n jo ijo ibile

Àgbékalẹ̀ èdè wọn

àtúnṣe

Èdè àwọn ìgbò náà tún jẹ mọ́ ẹbí Niger-Congo language family. Èdè wọ́n pín sí oríṣríṣi ẹ̀ka èdè.[15] The Igbo homeland straddles the lower Niger River, east and south of the Edoid and Idomoid groups, and west of the Ibibioid (Cross River) cluster.

Iṣẹ́ wọn

àtúnṣe

Ohun tí wọ́n mọ àwọn èyà yí mọ̀ ni iṣẹ́ ọnà, iṣẹ́ àgbẹ̀ àti iṣẹ́ òwò ṣíṣe. Lára àwọn ohun ọ̀gbìn tí wọ́n sábà ma ń gbìn jù ni Iṣu,[16] bẹ̀ẹ́ ni wọ́n ma ń gbin ẹ̀gẹ́ àti taro.[17]

Àwọn Ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. [1] Archived 2018-01-29 at the Wayback Machine. at CIA World Factbook: Nigeria country profile "Igbo 20.2%" out of a population of 214 million (2020 estimate). There are over 10 million Igbo living outside Nigeria. They are significant Igbo populations residing in most African countries and they are found in all corners of the globe, no matter how remote.
  2. Nwangwa, Shirley Ngozi (26 November 2018). "Why It Matters That Alex Trebek Mispronounced The Name Of My People On 'Jeopardy!'". Huffington Post. https://www.huffingtonpost.com/entry/alex-trebek-jeopardy-pronounciation_us_5bef2bd9e4b07573881e87ce. Retrieved 26 November 2018. 
  3. Àdàkọ:Cite Oxford Dictionaries
  4. "Igbo". Collins English Dictionary. HarperCollins. Retrieved 25 July 2019. 
  5. Àdàkọ:Cite Merriam-Webster
  6. Isichei, Elizabeth (1978). Igbo Worlds. Institute for the Study of Human Issues. 
  7. "Àdàkọ:Cite EB1911
  8. Lovejoy, Paul (2000). Identity in the Shadow of Slavery. Continuum International Publishing Group. p. 58. ISBN 978-0-8264-4725-8. https://books.google.com/?id=yEHVCsSFRUcC&pg=PA58.  Floyd, E. Randall (2002). In the Realm of Ghosts and Hauntings. Harbor House. p. 51. ISBN 978-1-891799-06-8. https://books.google.com/?id=T8p8OyMHWTYC&pg=PA51.  Cassidy, Frederic Gomes; Robert Brock Le Page (2002). A Dictionary of Jamaican English (2nd ed.). University of the West Indies Press. p. 168. ISBN 978-976-640-127-6. https://books.google.com/?id=_lmFzFgsTZYC&pg=PA168. 
  9. Equiano, Olaudah (1837). The Interesting Narrative of the Life of Olaudah Equiano. I. Knapp. p. 27. https://books.google.com/?id=FXVkAAAAMAAJ&pg=PA27. 
  10. Obichere, Boniface I. (1982). Studies in Southern Nigerian History: A Festschrift for Joseph Christopher Okwudili Anene 1918–68. Routledge. p. 207. ISBN 978-0-7146-3106-6. https://books.google.com/?id=FYFxE8-uSa4C&pg=PA207. 
  11. "The Igbo People - Origins & History". www.faculty.ucr.edu. Retrieved 2019-04-22. 
  12. Slattery, Katharine. "The Igbo People – Origins & History". www.faculty.ucr.edu. School of English, Queen's University of Belfast. Retrieved April 20, 2016. 
  13. Chigere, Nkem Hyginus (2000). Foreign Missionary Background and Indigenous Evangelization in Igboland: Igboland and The Igbo People of Nigeria. Transaction Publishers, USA. p. 17. ISBN 978-3-8258-4964-1. https://books.google.com/?id=sAY8aQz4ztEC&pg=PA17&lpg=PA17&dq=igbo+in+the+east+and+west+of+niger#v=onepage. Retrieved January 17, 2016. 
  14. Williams, Lizzie (2008). Nigeria: The Bradt Travel Guide. Bradt Travel Guides. p. 32. ISBN 978-1-84162-239-2. https://books.google.com/?id=fwuQ71ZbaOcC&pg=PA32. 
  15. Fardon, Richard; Furniss, Graham (1994). African languages, development and the state. Routledge. p. 66. ISBN 978-0-415-09476-4. https://books.google.com/?id=_34ReDEC2hMC&pg=PA66. Retrieved 2009-04-12. 
  16. Agwu, Kene. "Yam and the Igbos". BBC Birmingham. Retrieved 2008-11-24. 
  17. "Igbo". Britannica Online Encyclopedia. Retrieved 2009-02-01.