Omolade
Ọmọladé jẹ orúkọ ọmọ Naijiria. O tumo si" Ọmọ ni ade. " [1] nígbà mìíràn won man pe ni Moladé tabi Ladé.
Awọn eniyan olokiki pẹlu orukọ
àtúnṣe- Ajibade Omolade (ojoibi 1984), agbaboolu Naijiria
- Akeem Omolade (ojoibi 1983), agbaboolu Naijiria
- Omolade Akinremi (ojoibi 1974), omo Naijiria
- Abisola <b id="mwFw">Omolade</b> (ojoibi 1974), oludari ise ona Naijiria, onise isejade, ayaba ẹwa ati oniṣiro tẹlẹ.
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.yorubaname.com/entries/omolade