Omoniyi Caleb Olubolade
Olóṣèlú
Omoniyi Caleb Olubolade (ojoibi 30 November 1954) je Navy Captain totifeyinti ni ibise ologun ojuomi orile-ede Naijiria ati Gomina Ipinle Bayelsa tele. O je yiyansipo Alakoso Ojuse Pataki ninu kabineti Aare Goodluck Jonathan ni 6 Osu Kerin, 2010.
Omoniyi Caleb Olubolade | |
---|---|
Alamojuto Ipnle Bayelsa | |
In office 27 June 1997 – 9 July 1998 | |
Asíwájú | Habu Daura |
Arọ́pò | Paul Obi |
Alakoso awon Ojuse Pataki | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 6 April 2010 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kọkànlá 1954 Ipoti-Ekiti, AII Ijero, Ipinle Ekiti, Nigeria |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |