Omoyele Sowore (ti a bi ni ojo kerindinlogun osu keji odun 1971, 16-02-1971) je omo orile-ede Naijiria, ajafeto omo eniyan. [1] O dije dupo Aare orile-ede Nàìjirià labe egbé olósèlú "african action congress" lodun 2019, oun naa ni oludasile ile-ise iwe-iroyin elero atagba, Sahara Reporters. Ni ojo keta osu kejo odun 2019, awon olopaa otelemuye fi sinkun ofin mu Sowore nitori o se agbateru ifehonuhan lati gba ijoba lona aito.[2]

Omoyele Sowore
refer to caption
Sowore ní ọdun 2016
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kejì 1971 (1971-02-16) (ọmọ ọdún 53)
Ondo State, Nigeria
Ẹ̀kọ́University of Lagos
Columbia University
Iṣẹ́Human rights activist, blogger, writer, lecturer
Political partyAfrican Action Congress (2018–present
Olólùfẹ́Opeyemi Sowore (m. 2004)
Websitesaharareporters.com/

Àárò Ayé àti èkó rè

àtúnṣe

Yele Sowore jé omo Ese-Odo, Ipinle Ondo ni Guusu Iwọ-oorun Nàìjirià, a bi ni agbegbe Niger Delta nibi ti o ti dagba ni ile olorogun pẹlu ọmọ mẹrindilogun. [3] Nígbà tí ópé omo odún mejila, o kọ bí a se ún wa okada kí o le ma lọ sí odò ní àárò ojojumo láti peja fun gbogbo ẹbi rẹ ki o to lọ si ile-iwe. Sowore keko nipa "Geography and Planning" ni Yunifasiti ti ìlú èkó laarin odun 1989 si 1995, óparíparish notori pé le(expelled) kuro lara àwon akóèkó ilé-ìwé rè ní emeji nitori òrò tí ójo mó oselu ati ìjà fún ètó omo ilé-ìwé. [4] Ó jẹ́ Ààrẹ Ìjọba "student union government" ti Yunifásítì ti Èkó láàárín ọdún 1992 sí 1994. Sowore gbà àmì-èye master degree ní "public administration" ní yunifásitì ti Columbia. [5]

Sahara Reporters

àtúnṣe

Sowore dá Sahara reporters kalè ni odún 2006 ní ìlú New York láti lati gbogun ti iwa ibaje ati ti ijọba tí kò tọ. Ilé-ìsé Ford Foundation ati Omidyar Foundation ní óún se atileyin owó fún ilé ise Sahara Reporters . Gẹgẹbi ofin rè, Sahara ko ún gba ipolowo tàbí atilẹyin owo lati ọdọ ijọba Naijiria. [6]

Ìdíje fún ipò ààré

àtúnṣe

Ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 2018, Sowore kéde èrò rẹ̀ láti díje fún ààrẹ nínú ìdìbò gbogbogbòo 2019 tí Nàìjíríà [7] Ni Oṣu Kẹjọ ọdun 2018, o dá egbe oṣelu kan tí a ń pè ní "African Action Congress" (AAC) kale. Ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹwàá ọdún 2018, a se ìdìbò alabele tí egbe oselu AAC, Omoyele Sowore sí jáde láìsí àtakò gẹ́gẹ́ bí oludije Ààrẹ fún ẹgbẹ́ náà [8] bí o tile jé wipe ofidi remi nínú ìdìbò gbogbogbò odun 2019, Sowore ní ìbò 33,953, èyí tí ómú kó jé eni ekarun tí ó ní ìbò tópòjù. [9]

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
Omoyele Sowore
ọmọnìyàn
ẹ̀yàakọ  
country of citizenshipNàìjíríà  
ọjó ìbí16 Oṣù Èrèlé 1971  
ìlú ìbíOndo State  
spouseOpeyemi Sowore  
writing languagegẹ̀ẹ́sì  
employerAfrican Action Congress, Sahara Reporters  
kẹ́ẹ̀kọ́ níYunifásítì ìlú Èkó, School of International and Public Affairs, Columbia University  
academic degreemaster's degree  
member of political partyAfrican Action Congress  
candidacy in election2019 Nigerian presidential election, 2023 Nigerian presidential election  
located in protected areaAbia State  
significant eventYele Sowore Treason Charges  
official websitehttp://saharareporters.com/  
personal pronounL485  
  1. "Omoyele Sowore". Wikipedia. 2016-03-09. Retrieved 2019-09-30. 
  2. Published (2015-12-15). "Court orders remand of Sowore, co-defendant in DSS custody". Punch Newspapers. Retrieved 2019-09-30. 
  3. "Meet Omoyele Sowore, The Founder Of Sahara Reporters [Photos]". Information Nigeria. 2015-10-24. Retrieved 2022-04-10. 
  4. "Sowore Was Arrested By The DSS Ahead Of The Planned Protest". EveryEvery. 2019-12-13. Retrieved 2022-04-10. 
  5. "Omoyele Sowore (Saharareporters.com), Blogger, Writer, Lecturer, Human rights activist, Nigeria Personality Profiles". Nigeriagalleria. 1971-02-16. Retrieved 2022-04-11. 
  6. Shenon, Philip (2017-07-14). "Sahara Reporters: Uncovering Nigeria’s Corruption". The Daily Beast. Retrieved 2022-04-11. 
  7. Bada, Gbenga (2018-02-25). "SaharaReporters publisher says Buhari has no brain, declares for president". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-04-11. 
  8. Ogala, George (2018-10-07). "2019: Sowore emerges AAC presidential candidate". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-04-11. 
  9. Toromade, Samson (2019-02-27). "Votes won by all 73 presidential candidates in 2019 election". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-04-11.