African Action Congress
African Action Congress (AAC) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí Ọmọyẹlé Ṣọ̀wọ̀rẹ́, olùdásílẹ̀ olùtẹ̀ ìwé-ìròyìn, Sahara Reporters dá silẹ ní Nigeria lọ́dún 2018.[3]
African Action Congress | |
---|---|
Olórí | Omoyele Sowore |
Spokesperson | Adeyeye Olorunfemi |
Olùdásílẹ̀ | Omoyele Sowore |
Ibùjúkòó | Office 011, Bolingo Hotel & Towers, (Office Block), Plot 777Independent Avenue, beside American Embassy, Central Business Direct, Abuja. |
Ọ̀rọ̀àbá | Eco-socialism Pan-Africanism Anti-imperialism Anti-capitalism[1] |
Ipò olóṣèlú | Left-wing |
National affiliation | Coalition for Revolution (CORE) |
Ìbáṣepọ̀ akáríayé | Progressive International (via the Coalition for Revolution (CORE))[2] |
Ibiìtakùn | |
aacparty.org/ | |
Ìṣèlú ilẹ̀ Nigeria |
Ọ̀rọ̀-ìmóríwú ẹgbẹ́ òṣèlú náà ni: Take it back, tí ó túmọ̀ sí gbà á padà. Alága ẹgbẹ́ òṣèlú náà tí àjọ ìdìbò, INEC mọ̀ lábẹ́ òfin ni Omoyẹlé Ṣòwòrẹ́. [4][5][6] Lọ́jọ́ ajé, ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 2019, AAC kéde ìlẹ́lẹ́gbẹ́ Leonard Nzenwa àti ìdádúró ránpé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ mìíràn fún ìwà àjẹbánu, ìṣowó báṣubàṣu àti àwọn ìhùwàtako ẹgbẹ́.[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "A People's Manifesto for Total Liberation: The AAC Program for Revolutionary Transformation of Nigeria, 2022" (PDF). African Action Congress. 2022. Retrieved 19 October 2023.
- ↑ "Coalition for Revolution (CORE)". Progressive International.
- ↑ "Sowore unveils new party". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-08-16. Retrieved 2024-07-06.
- ↑ "African Action Congress – INEC Nigeria". inecnigeria.org. Independent National Electoral Commission. Archived from the original on 1 July 2022. Retrieved 11 July 2021.
- ↑ "Sowore support group registers political party". 14 August 2018.
- ↑ "Sowore To Contest Presidential Election On The Platform of African Action Congress". Sahara Reporters. 14 August 2018.
- ↑ "AAC expels Nzenwa from party". Vanguard. Retrieved July 6, 2024.