Omupo
Omupo tabi Omu-ipo je ilu ad'ayeba ti o je mo Igbomina ni Ipinle Kwara.[1] O je okan lara awon ilu ti o l'okiki ni ijoba ibile Ifelodun.[2] O wa ni agbegbe guusu-ila oorun ipinle naa. Oun ni olu-ilu fun agbegbe merin-le-logbon ti o wa ni adugbo Omupo, oun tun ni olu-ilu agbegbe Omupo/Idofian ni ijoba ibile Ifelodun, oun kanna ni o si je gboogi agbegbe idibo fun yiyan asoju si ile igbimo asofin ti ipinle Kwara fun ipin asofin Omupo lati odun 1979.
Agbegbe
àtúnṣeOmupo wa ni apa 8°16′28″N 4°47′49″E / 8.274349°N 4.796948°E ila-oorun gege bi o ti wa lori aworan agbaye, alaye ipo ati alaye agbegbe ni soki. O je iwon maili igba-din-mesan (kilomita meji-din loodunrun le mewa) guusu-iwo oorun si Abuja, maili merin-le-logun (kilomita meji-din-logoji) guusu-ila oorun si Ilorin, maili meta (kilomita marun) ariwa-iwo oorun si Ajasse Ipo, maili mewa (kilomita merin-din-logun) ariwa-ila oorun si Offa, maili meji-din-logoje 138 miles (kilomita igba le meji-le-logun) ariwa-ila oorun si Ibadan ati maili igba le meta-din-logun (kilomita oodunrun le laadota) ariwa-ila oorun si Eko.
Awon itokasi
àtúnṣe- ↑ Online, Tribune (2017-02-16). "Suspected ritualists behead two children in Omupo, Kwara". Tribune. Retrieved 2018-05-01.
- ↑ "CBN: Nigerians’ Inability to Access Funds Reason for Continued Economic Hardship". THISDAYLIVE. 2017-09-14. Retrieved 2018-05-01.