My name is Adeseyoju, Toyosi Praise, I'm an undergraduate finalist of Linguistics and Yoruba, from the University of Lagos. I joined Wikipedia in 2022, and I've been an active contributor to the Yoruba Wikipedia ever since then. My passion for contributing to free knowledge in the Yoruba language, love for the promotion and development of the language and as well as my zeal towards keeping the language from going into extinction is one of my major reasons for joining the Wikimedia community. I am the current president of Yoruba Wikipedia Fan-club in University of Lagos, which was established in 2022. I have participated in several contests and I have over 100 articles written in Yoruba language.

Orúkọ mi ni Adéṣèyojù, Tóyọ̀sí Praise; mo jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ti ẹ̀kọ́ Lìǹgúísíìkì àti èdè Yorùbá ní ilé ìwé gíga Fásitì ìjọba àpapọ̀ tí Ìpínlẹ̀ Èkó ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Mo darapọ̀ mọ́ ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia ní ọdún 2022. Ìpinnu mi lórí ìwé ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikipedia yìí ni láti ṣe àfikún sí èdè Yorùbá. Ìfẹ́ tí mo ní sí èdè Yorùbá, ìgbìyànjú láti gbé èdè náà lárugẹ àti ìtara kí èdè náà má parun ló mú mi darapọ̀ mọ́ Wikipedia. Lọ́wọ́ lọ́wọ́ èmi ni mo jẹ́ ààrẹ Wikipedia Fan-club ní Unilag, tí wọn ṣe ìdásílẹ rẹ̀ ní ọdún 2022.

Ìfitónilétí oníṣe fún Bábẹ́lì
en-5 This user has professional knowledge of English.
yo-N Oníṣe yìí èdè abínibí rẹ̀ ni Yorùbá.
pcm-3 This user has advanced knowledge of Naijá.
fr-3 Cet utilisateur dispose de connaissances avancées en français.
ig-1 Òjìème â nwèrè nghọta asụ̀sụ̀ Ìgbò ǹkè ụ̀dị̀ǹkịtị̀.
Àwọn oníṣe gẹ́gẹ́bí èdè