Tunde adegoke
Ilu ati Molebi Tunde Tunde Adegoke je omo ilu Ojo ni Ijoba ibile Egbedore ni Ipinle Osun. Tunde je omo keji ti baba ati iya re bi ninu awon meta, Tunde ni egbon obinrin kan ti oruko re nje Fatimo Adegoke, osi ni aburo kan ti oruko re nje Waliu Adeniyi Adegoke.
Ile Iwe Tunde Tunde bere ile iwe akoko re ni Golden Care Primary School ni Ede, ijoba ibile ariwa Ede ni igba die seyin, Tunde ka iwe re de ipele keji ni kilasi kerin ko to di wipe o tesiwaju lati pari ile iwe akoko bere re ni Ile iwe ti owa ni ogba awon ologun ni Army Children Primary School Oke Gada Ede ni odun 2001 leyin ti o tesiwaju ninu eko re losi ile iwe Ede Muslim Grammar School ni Ede lati pari ile iwe sekondiri re, ti osi pari ni odun 2007. Leyin ti Tunde pari eko re ni Ile iwe yii, o tesiwaju ile eko re ni Vico Hope International School ni Ilu Iwo nitori wipe esi WAEC re ni ile iwe Ede Muslim Grammar School ko pe lati tesiwaju lo si ile iwe giga.
Tunde pari pelu esi risoti to peye ni ile iwe Vico Hope International School Iwo, leyin ti o tesiwaju eko re ni ile iwe politekiniki ijoba apapo ni Ilu Ede nibiti o ti ni dipiloma ni Statistics ti osi pari eko re ni osu kejo odun 2011. Leyin eyii, Tunde pada si ile iwe giga unifasiti ilu Ilorin ni odun 2012 lati pari eko re leleyi to si pari ni osu keje odun 2015.