Onos Ariyo
Onoriode Ebiere Ariyo tí a mọ̀ sí Onos Ariyo jẹ́ akọrin àti akọrin tí ó da lórílẹ̀ ẹ̀dẹ̀ Nàìjíríà. A mọ̀ ọ́n jùlọ sí orin ìyìn rẹ̀ “Alagbara” tí ó jẹ́ àkórí Orin tí ọ kọ tí Ọ̀gbẹ́ni Wilson Joel bá a jẹ́ agbéjáde rẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Ni Oṣù Kẹsàn án ọdún 2018, o jẹ́ ẹni Kan tí a dárúkọ lára àwọn tí o jẹ́ gbajúmọ̀ àti àwọn tí ọ jẹ́ ìkíní títí dé ti ọgọ́rùn ún Àwọn ènìyàn ti o ní ipa jùlọ ti ilẹ̀ Áfíríkà (MIPAD).
Onos Ariyo | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Onoriode Ebiere Bikawei |
Irú orin | |
Occupation(s) | Singer, songwriter |
Years active | 2009–present |
Labels | Mirus |
Associated acts | Nikki Laoye, Glowreeyah Briamah, Sammie Okposo, Wilson Joel |
Ibẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeA bí Onos ni ìpínlẹ̀ Delta ni Gúúsù Nàìjíríà níbi tí ó ti gba ẹ̀kọ̀ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ áti gírámà lẹ́yìn ìgbà tí ó gba ìdàsílẹ̀ si Delta State University, Abraka níbi tí ó ti parí ẹ̀kọ́ gíga àkọ́kọ́ ni èdè Faranse. Onos ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ rẹ̀ láti ìgbà tí o ti wà ni ilé ẹ̀kọ́ alakọbẹrẹ, [1] tí o šì jẹ́ akópa lára àwọn tí wọ́n wà ní onírúurú ẹgbẹ́ akọrin àti àwọn ẹgbẹ ṣáájú ki o to lọ si ìlú Èkó ni ọdún 2004 níbi tí o ti bẹ̀rẹ̀ gbígbà sílẹ̀ orin àkọ́kọ́ rẹ, “Ijó” ti FLO ṣe jáde. .
Iṣẹ́
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedworship1