Nikki Laoye
Akọrin obìnrin
Oyenike Laoye, tí a mọ iṣẹ rẹ sí agbohùn olórin sílẹ̀, olórin ní,ẹnití o máa ṣe ohun kan fún àwọn ènìyàn , o máa n ko orin sí lè , oníjó, òṣèré ní. Tí a mọ̀ ipa takuntakun tí òun kò nínú orin , atí eré orí ìtàgé.[1] Gẹ́gẹ́ bí agbohùn olórin sílè, ilé iṣé orin Laoye o tí gbà ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì ẹ̀yẹ bí Obìnrin tó dáńgájiá nínú orin kíkọ ní ọdún 2013[2] àti All African Music Awards (AFRIMA) ní ọdún 2014 fún Best Female Artiste in African Inspirational Music.[3][4] Ó gbajúmọ̀ fún orin tó kọ ní ọdún 2006, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Never felt this Way before, orin oníjó ti ọdún 2013 "1-2-3", orin "Only You", èyí tí ó kọ pẹ̀lú Seyi Shay ní ọdún 2006 àti orin Onyeuwaoma pẹ̀lú Banky W.[5]
Nikki Laoye | |
---|---|
Nikki Laoye | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Oyenike Laoye |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejìlá 1980 Lagos, Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Osun State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2005–present |
Labels | Wahala Media Entertainment |
Website | reverbnation.com/nikkilaoye/nikkilaoye |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "10,000 Lagosians rock Inspiration FM praise jam". Vanguard Newspaper (Lagos, Nigeria). 1 January 2010. http://www.vanguardngr.com/2010/01/10000-lagosians-rock-inspiration-fm-praise-jam//.
- ↑ Osaz, Tony (27 December 2013). "Olamide wins big @ Headies 2013 + full list of winners". Vanguard (Lagos, Nigeria). https://www.vanguardngr.com/2013/12/olamide-wins-big-headies-2013-full-list-winners/.
- ↑ Ade, Ola (15 November 2015). "AFRIMA The Chips Go Down Tonight". Vanguard (Lagos, Nigeria). https://www.vanguardngr.com/2015/11/afrima-awards-the-chips-go-down-tonight/.
- ↑ Showemimo, Dayo (31 December 2014). "AFRIMA award is Nikki Laoye's 5th in 2014". TheNet Newspaper (Lagos, Nigeria). http://thenet.ng/2014/12/afrima-award-is-nikki-laoyes-5th-in-2014/.
- ↑ Adesida, Olumide (14 February 2016). "MUSIC: Nikki Laoye feat. Banky W – Onyeuwaoma". TheNet Newspaper (Lagos, Nigeria). http://thenet.ng/2016/02/music-nikki-laoye-feat-banky-w-onyeuwaoma/.