Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sósíálístì ilẹ̀ Kroatíà

Socijalistička Republika Hrvatska
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Sósíálístì ilẹ̀ Kroatíà
Socialist Republic of Croatia

A federal unit of the
Socialist Federal Republic of Yugoslavia

1943 — 1991
[[Image:|80px]]
Flag Coat of arms
OlúìlúZagreb
Èdè oníbiṣẹ́ede Kroatia
Established
In the SFRY:
 - Since
 - Until
June 13, 1943

June 13, 1943
June 25, 1991
Area
 - Total
 - Water
Ranked 2nd in the SFRY
56,524 km²
0.227%
Population
 - Total 
 - Density
Ranked 2nd in the SFRY
4,784,265
84.6/km²
CurrencyYugoslav dinar (dinar)
Time zone UTC + 1

Orile-ede Olominira Sosialisti ile Kroatia (Socialist Republic of Croatia to unje kikekuru bi SR Croatia; ede Kroatia: Socijalistička Republika Hrvatska, SR Hrvatska) je orile-ede sosialisti ati orile-ede alabagbepo alaselorile ti Orile-ede Olominira Sosialisti Apapo ile Yugoslafia tele. Ohun lo siwaju Orile-ede Olominira ile Kroatia ode oni. O di apa Apapo Toseluarailu Yugoslafia ni 1943. Ni 1990 [1][2], o je titundasile bi Kroatia, o gba sistemu egbe oloselu pupo ati okowo oja ainidekun mu (free market economy).