Oreoluwa Lesi je̩  o̩kan pataki ninu onisowo to gbaju gbaja o̩mo̩ Naijiria pe̩lu onise̩ aje to gba e̩ko lati ile O̩ba UK. Owun ni oludasile ati oludari ile ise̩ Women's Technology Empowerment Centre (W.TEC), aagbari olu ile ise̩ ti ki se fun eree, a non-profit organisation eyi to n ro awo̩n obinrin pelu o̩mo̩de lobinrin lagbara ni awujo lori imo̩ e̩ko̩ ati imo̩ e̩ro̩.[1] o̩dun 2008 ni wo̩n da ile ise̩ yi sile̩. Oreoluwa Lesi wa ninu e̩le̩gbe̩ Ashoka. O tigba awo̩duu ABIE, fun oluranlo̩wo̩ iyipada.

Oreoluwa Lesi
IbùgbéLagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Gbajúmọ̀ fún
  • Information Technology Literacy
  • Girls Empowerment
TitleExecutive director

Igba ewee ati e̩ko̩

àtúnṣe

Ni ilu Naijiria ni Lesi ti lo igba ewee re̩. Onise̩ e̩ro ina mo̩namo̩na ni baba re̩, lati kekere loti ni ife si e̩ro ayara bi asha, eyi ti ose okunfa ise̩da e̩ro agbe ise̩ jade (software application) ti ohun elo fun soobu atawe (bookshop) awon obi re̩.[2]

Ile iwe Queen's College, Lagos, ni Oreoluwa Lesi lo̩. Le̩yin eyi lo lo̩ kawe si  ninu imo̩ siseto ko̩smputa, (diploma course in computer programming). O te̩ siwaju lo̩ si ilu Oba, (United Kingdom) lo̩ kawe siwaju lori eko̩ imo̩ ọrọ aje, (economics) to si gba amin ẹyẹẹ bachelor's degree lati University of Essex. O tun gba amin ẹye oniyi, (master's degree) ninu imọ atupọ, oniruwe pelu isakoso alaye, (analysis, design and management information) ni London School of Economics and Political Science.[3] Arabinrin ti a n sọrọ ẹ yi ti mu ayipada rere ba awọn eyan bi 12000 tojẹ omode birin nilu Naijiria. Eyi ni anfani towa lati olu ile isẹ aladani, NGO, . O te̩  siwaju ninu ekọ Applied Sciences ni Harvard University Extension School

Iṣẹ gboogi to yan laayo

àtúnṣe

Oṣiṣẹ ni UK pelu Lonadek Oil and Gas Consultancy nibi ti o tin mojuto CSR Initiative-2020. O tun ṣiṣẹ pẹlu EDC nilu oba, United State lori research project. Ọdun 2005 lopada si ilẹ Naijiria. Ni ọdun 2008 lo da W.TEC silẹ.[4] Won fun ni oye, fellow of Ashoka ni ọdun 2013. Nigba to di ọdun 2009, o tun gba amin ẹyẹẹ ABIE Award Winners, oluyipada rere, Change Agent.[5][6]

Ayee ara eni 

àtúnṣe

Ayaa Gboyega Lesi ni arabinrin yi. Ilu eko ni won n gbe. Lagos.[7]

Awon iwe atẹjade

àtúnṣe
Year Title Work
2004 Making the Most of On-line Learning: An Introduction to Learning on the Internet’ Education Development Center[8]
2006 ‘Telling Our Own Stories: African Women Blogging for Social Change’ Gender & Development Journal[9]
2013 Radio for Women’s Development Examining the Relationship between Access and Impact Nokoko Institute of African Studies Carleton University Ottawa, Canada) 2013(3)[10]

Awon itokasi

àtúnṣe
  1. Vista, Woman (21 October 2012). "We’re empowering girls for IT devt – Oreoluwa Somolu". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2012/10/were-empowering-girls-for-it-devt-oreoluwa-somolu/. Retrieved 13 October 2016. 
  2. The Adminstrator. "Ashoka Fellow". Ashoka. Retrieved 14 October 2016. 
  3. Bimbola Segun-Amag. "CPAfrica Intervies Oreoluwa Somolu Lesi of Women's Technology Empowerment Centre". CPAfrica. Archived from the original on 1 April 2019. Retrieved 14 October 2016. 
  4. Empty citation (help) 
  5. Empty citation (help) 
  6. Empty citation (help) 
  7. Empty citation (help) 
  8. Empty citation (help) 
  9. Empty citation (help) 
  10. Empty citation (help) 

Awọn asopọ ita

àtúnṣe