Orin Odu
Àdàkọ:Infobox album Odu jẹ́ àwo orin kan tí Olórín Jùjú orílè èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmò tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ King Sunny Adé. Ó gbé orin náà jáde ní ọdún 1998 láti ọwọ́ Mesa Atlantic Record. Wọ́n ṣètò kíkọ àti kíkọ̀ orin náà ni Dockside Studios ni Maurice ni ilu Louisiana, Ọ̀gbẹ́ni Andrew Frankel ni ó ṣe alábòójútó orin náà àti fífi àwọn èròjà Ìbílè tí Yorùbá si. [1][2] Odù túmọ̀ ni èdè Yorùbá sí Ọ̀pẹ̀lẹ̀Ifá.
Leo Stanley tí All music fún Àwo orin Odù ni Àmì ìrawọ̀ mẹ́rìn-ín nínú márùn-ún látàrí pé orin náà ní pọn. Ó pé orin náà kún fún Àṣà, àti pé ó kún fún oríṣiríṣi nǹkan tí ó jẹ́ mọ́ èdè Yorùbá.[3] Ní ọdún 1999, àwọn Àjọ Àmì ẹ̀yẹ Grammy yan orin náà gẹ́gẹ́ bí Orin tí ó Dára jù tí ó tún gbayì jùlọ ni àgbáyé Best World Music Album.[4]
Àwọn orin inú àwo Odù
àtúnṣe- "Jigi Jigi Isapa" — 5:36
- "Easy Motion Tourist" — 5:59
- "Alaji Rasaki" — 5:19
- "Mo Ri Keke Kan" — 4:04
- "Kiti Kiti" — 6:18
- "Natuba" — 6:15
- "Aiye Nreti Eleya Mi" — 12:50
- "Ibi Won Ri O" — 3:33
- "Kawa to Bere" — 5:32
- "Eri Okan (Conscience)" — 9:56
- "Kini Mba Ro" — 4:35
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "KSA — Father of Juju Music", Leadership, allAfrica, 29 May 2011, retrieved 17 October 2011
- ↑ Simonini, Ross (17 June 2009), "King Sunny Adé's Lengthy Reign", SF Weekly, Village Voice Media, archived from the original on 13 January 2014, retrieved 17 October 2011
- ↑ Stanley, Leo, "Odu — King Sunny Ade > Review", Allmusic, Rovi Corporation, retrieved 17 October 2011
- ↑ Nzewi, Meki; Nzewi, Odyke (2007), A Contemporary Study of Musical Arts: Illuminations, Reflections and Explorations, African Minds, ISBN 1-920051-65-1