Orun Mooru (Heaven is Hot) jẹ́ eré apanilẹ́rìn-ín tí a gbé jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1982. Adarí eré náà ni Ola Balogun eré náà jẹ́ gbígbé jáde láti ọwọ́ Moses Olaiya (Baba Sala). Eré náà sọ ìtàn nípa ọkùnrin olókoòwò tí ó ti fi ìgbà kan lówó rí, ẹni tí ó bọ́ sí ọwọ́ babaláwo èké kan nípa ṣíṣe ògùn àti tètè lówó èyí tí kò bọ́ síi get-rich-quick scheme, lẹ́yìn èyí ni ó wá gbèrò àti gbẹ̀mí ara rẹ̀.[1]

Orun Mooru
AdaríOla Balogun
Olùgbékalẹ̀Moses Olaiya
Òǹkọ̀wéOla Balogun
Àwọn òṣèréMoses Olaiya
Ìyàwòrán sinimáTunde Kelani
Ilé-iṣẹ́ fíìmùAlawada Movies ltd.
Déètì àgbéjáde1982
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèYoruba
Ìnáwó₦1,500,000

Ìhun ìtàn

àtúnṣe

Orun Mooru sọ nípa ìtàn Karounwi (Moses Olaiya), ẹni tí ó jẹ ahun-apẹ̀rẹ̀ (basketmaker) tí ó ń gbé ní ìlú tí wọ́n tíń pa ẹja. Ìsàpèpadà ìrírí jẹ́ kí á mọ̀ pé ó ti fi ìgbà kan lògbà rí gẹ́gẹ́ bíi oníṣòwò, kí ó tó bọ́ sọ́wọ́ babaláwo èké nípa níní èrò pé òun le di olówó tabua.

Karounwi gba owó-ìyá tótó ₦500 láti ọwọ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀. Ó pàdánù gbogbo owó; ìdajì sí ọwọ́ olè alọ́nilọ́wọ́gbà, èyí tí ó ṣẹ́kù tí ó kó pamọ́ sínú ìlú ni ìyàwó rẹ̀ gbé lọ láti fi pàrọ̀ abọ́. Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ó sún un láti gbẹ̀mí ara rẹ̀ tí ó sì ti ibẹ̀ di ẹni ilẹ̀pa tí ó sì bá ara rẹ̀ ní ìlú àwọn oku.

Iku (means: Death) Ikú sọ fún un pé òun kò retí rẹ̀ torí àsìkò rẹ̀ kò rí ì tó, ni Karounwi bá lọ Ayọ̀ (means: Joy), ẹni tí ó dá appadàsí ilé ayé pẹ̀lú ẹyin agbára méjì àti méjì nínú àwọn ọmọ lẹ́yìn rẹ̀.

Nígbà tí ó dé inú ayé ni ó bá ara rẹ̀ nínú ilé ńlá kan, Karounwi bá àwọn ọmọ ẹ̀yìn Ayo méjèèjì lòpọ̀, lẹ́yìn èyí ni ó fọ́ ẹyin kan nínú méjì tí Ayo fún un èyí tí ó yí padà di owó jaburata. Lẹ́yìn èyí ni ó kọ etí ikún sí ìmọ̀ràn tí wọ́n fún un láti tẹ̀lé, ó fọ́ ẹyin kejì èyí tí ó yí padà tí ó di ikú.

Àwọn òṣèré

àtúnṣe

Gbígbé jáde

àtúnṣe

Wọ́n ya ojúlówó eré náà sí 35 mm film, ṣùgbọ́n tí wọ́n dín in kù sí 16 mm film fún gbígbé ká àti ṣíṣe lafihàn.[2]

Wọ́n ya ayé kejì eré náà ní Osun Grove, Osogbo.[1]

Àríwísí

àtúnṣe

Orun Mooru jẹ́ eré tó àṣeyọrí, kí wọ́n tó gé àṣeyọrí rẹ̀ kúrú nípa ṣíṣe ẹ̀dà rẹ̀, kí ó tó padà wọ orí ìtàgé. [1]

Critical reception

àtúnṣe

Kenneth W. Harrow states: "The themes of over-reaching greed and wild swings from the village life from the lavish property and back again, are close to the heart Nigerian national experience during the oil boom years [...] Propelled by his moral wills, Baba Sala bounces among four sharply opposing realms".[1]

Not long after the theatrical release of Orun Mooru, it got pirated and bootlegged following the theft of the film's master celluloid tape.[1][2] The piracy happened before the end of the theatrical run of the film; several cinemas in different cities across the country screened the film without being licensed to do so and remuneration never reached the producers.[3] The loss incurred as a result of this piracy significantly affected the career of Moses Olaiya in the film industry, as well as his personal life.[4][5][2][6][7] The piracy of Orun Mooru has been reported as a first major incidence of piracy in the Nigerian film industry.[2][8][9]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 Harrow, Kenneth W. (1999) (in en). African Cinema: Postcolonial and Feminist Readings. Africa World Press. ISBN 9780865436978. https://books.google.com/books?id=kRR2fBv2NhUC&q=orun%2520mooru&pg=PA160. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "I Was The First Actor To Be Dealt With By Pirates -Baba Sala". www.nigeriafilms.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-24. 
  3. Makinde, Femi. "Baba Sala forgave those who pirated Orun Mooru before he died –Emmanuel, son". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-24. 
  4. (in en) Glendora Review. Glendora International (Nigeria) Limited. 2001. https://books.google.com/books?id=NsQwAQAAIAAJ&q=orun+mooru. 
  5. Bada, Gbenga. "7 movies produced by Baba Sala and which he played lead roles" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-24. 
  6. Adeyemo, Adeolu (2017-05-27). "Bala Sala: I never recovered from my Orun Mooru travails". www.newtelegraphng.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-25. Retrieved 2018-11-24. 
  7. "Things you didn't know about Moses Olaiya aka ( Baba Sala ) – INFORMATION NIGERIA". INFORMATION NIGERIA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-14. Retrieved 2018-11-24. 
  8. Odejimi, Segun (2018-10-08). "Moses Olaiya Adejumo (Baba Sala): The Comedy Legend Who Was Brutally Attacked By Pirates". TNS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-25. Retrieved 2018-11-25. 
  9. Adejumo-Ayibiowu, Oyindamola (2018-11-14). "Nigeria: Beyond Laughter, a Purvey of Baba Sala's Role in Nigeria's Economic Development". The Guardian (Lagos). Retrieved 2018-11-25.