Osai Ojigho tí wọ́n bí ní ọdún 1976, jẹ́ ògbójú ajàfẹ́tọ̀ọ́ ọmọnìyàn, amòfin àti oni kò-kárí ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ,[1] Òun ni títí di 2021 adarí àgbà fún ajọ Amnesty International's fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó tún ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí olùbádámòràn pàtàkì lábẹ́ Global Advisory Council fún àjọ Institute for African Women in Law (IAWL), ó sì wà lórí ipò àjọ board of Alliances for Africa.[2][3][4]

Osai Ojigho
Ọjọ́ìbí1976 (ọmọ ọdún 47–48)
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Country Director, Amnesty International Nigeria
Gbajúmọ̀ fúnLaw, human rights, advocacy, gender equality

Ibẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Ojigho ní Ìpínlẹ̀ Èkó sí inú ẹbí ọ̀gbẹ́ni Olóyè Mark Obu ati arabìnrin Theresa.[5] Ó gba dìgírì (LLB) nínú ìmọ̀ ofin ní ilé-ẹ̀kọ́ Lagos State University, ó sì gba oyè Master of Laws (LLM) ní ilé-ẹ̀kọ́ University of Wolverhampton, ní orílẹ̀-èdè United Kingdom.[6] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí amòfin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 2000. Ó gba ìwé-ẹ̀rí Diploma in International Human Rights láti ilé-ẹ̀kọ́ College of Law of England and Wales in 2010.[7]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Ní ọdún 2017,wọ́n yan Ojigho sí ipò adarí agba Director of Amnesty International in Nigeria, fún àwọn orílẹ̀-èdè gbogbo. [8]ní bi tí ó ti ń ṣe àbójútó ati ìpolongo tí ó ní ṣe pẹ̀lú Bring Back Our Girls ati End SARS[9][10][11] bẹ́ẹ̀ ni ó sì ń ṣe atìlẹyìn fún àwọn ìjàngbara ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn mìíràn rẹpẹtẹ bíi àìṣòdodo láwùjọ, ìfipá báni lòpọ̀, ìyànjẹ àwọn obinrin.[12][13] social injustice, housing rights and sexual and gender based violence.[14][15][16][17]

Àwọn amì-ẹ̀yẹ rẹ̀

àtúnṣe

Ní ọdún, wọ́n ka Ojigho mọ́ àwọn African Feminist Forum ní ilẹ̀ Adúláwọ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú méjìdínlógún tí wọ́n jẹ́ ajàfẹ́tọ̀ọ́ àwọn obinrin ní ilẹ̀ Adúláwọ̀.[18]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "PressReader.com - Your favorite newspapers and magazines.". www.pressreader.com. Retrieved 2020-06-23. 
  2. "Nigeria: Osai Ojigho joins Amnesty International Nigeria as new Country Director". www.amnesty.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-23. 
  3. "Osai Ojigho | The Mantle". www.themantle.com. Archived from the original on 2020-10-29. Retrieved 2020-10-26. 
  4. "Boardmembers". AFA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  5. "PressReader.com - Your favorite newspapers and magazines.". www.pressreader.com. Retrieved 2020-06-23. 
  6. "Amnesty appoints Osai Ojigho as Country Director for Nigeria". Financial Nigeria International Limited (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-23. 
  7. Woman.NG (2017-04-27). "Osai Ojigho Becomes Country Director Of Amnesty International In Nigeria". Woman.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-02-18. Retrieved 2020-10-26. 
  8. "Amnesty International announces Osai Ojigho as new Country Director". P.M. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-04-26. Retrieved 2020-10-26. 
  9. "Nigerian forces killed 12 peaceful protesters, Amnesty says". AP NEWS. 2020-10-21. Retrieved 2020-10-26. 
  10. AfricaNews (2020-10-22). "#EndSARSNow: NGO Says Justice "Needs to Be Served" in Nigeria". Africanews (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  11. Presse, AFP-Agence France. "Nigeria's Ban On Police Unit Is 'Lame': Amnesty". www.barrons.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  12. "Amnesty Sets Agenda to Address Nigeria's Human Rights Violations". Council on Foreign Relations (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  13. "Rights Group Calls for War Crimes Probe Against Nigeria's Military | Voice of America - English". www.voanews.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  14. "Nigeria: 30K Evicted, Defying Court". hlrn.org. Retrieved 2020-10-26. 
  15. ""They betrayed us" : Women who survived Boko Haram raped, starved and detained in Nigeria - Nigeria". ReliefWeb (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  16. "The NBA should have a sexual harassment policy". Legal Business (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-06-26. Retrieved 2020-10-26. 
  17. Services, Compiled from Wire (2018-05-25). "Boko Haram victims face abuse by Nigerian army". Daily Sabah (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-10-26. 
  18. "18 Phenomenal African Feminists to Know and Celebrate » African Feminist Forum". African Feminist Forum (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-05-04. Retrieved 2020-10-27.