Oshodi Tapa
Chief Oshodi Landuji Tapa (c. 1800 – 1868) jẹ́ Balógun Oba Kosoko àti ara àwọn olóyè tí ó lágbára jù lọ ní ààfin Oba Èkó.[citation needed]
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
àtúnṣeỌ̀pọ̀ gbàgbọ́ pé Oshodi Tapa wá láti ẹ̀yà Nupe[1] ní Bida tí ó wà lábé Oba Osinlokun.[2] Ìdílé Oshodi sọ wípé nígbà tí Tapa jẹ́ ọmọdé, àwọn olóko ẹrú pinu láti gbe sínú ọkọ omi Portugal tí ó ń lọ Amẹ́ríkà ṣùgbọ́n ó sá ó sì lọ sí àfin Oba Osinlokun fún àbò.[3]
Ìdìde rẹ̀
àtúnṣeNítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn tí ó ní, Oshodi Tapa di adúnàdúrà fún Oba Osinlokun.[4] Ọba Osinlokun rán ohun àti ẹrú míràn (Dada Antonio) lọ sí Brazil láti kọ́ èdè Portuguese, àti láti ní ìmò tí ó ṣe pàtàkì láti gba owó orí lọ́wọ́ àwọn òní òwò ẹrú Portugal.[5] Lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣiṣẹ́ fún Osilokun, Oshodi Tapa di ọ̀lùmọ̀ràn àti Balógun Oba Kosoko.[citation needed]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Cole, Patrick (1975-04-17). Modern and Traditional Elites in the Politics of Lagos. Cambridge University Press, Apr 17, 1975. p. 18. ISBN 9780521204392. https://archive.org/details/moderntraditiona0000cole/page/18.
- ↑ Whiteman, Kye (October 2013). Lagos: A Cultural History. Interlink Publishing, Oct 1, 2013. ISBN 9781623710408. https://books.google.com/books?id=byNFBAAAQBAJ&pg=PT188. Retrieved 21 December 2016.
- ↑ Folorunsho-Francis, Adebayo (2014-07-20). "How Oshodi Tapa Became A Lagosian". City Pulse. Archived from the original on 2018-04-05. Retrieved 2023-08-27.
- ↑ Mann, Kristin (2007-09-26). Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760--1900. Indiana University Press, Sep 26, 2007. p. 56. ISBN 9780253117083.
- ↑ Mann, Kristin (2007-09-26). Slavery and the Birth of an African City: Lagos, 1760--1900. Indiana University Press, Sep 26, 2007. p. 75. ISBN 9780253117083.