Otto Fritz Meyerhof ForMemRS[2] (April 12, 1884 – October 6, 1951) jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́nsì Jemánì ti ologun ati isomi ara eni tó gba ẹ̀bun Nobel fún ìwòsàn ati fisioloji ni odun 1922.

Otto Fritz Meyerhof
ÌbíApril 12, 1884
Hanover
AláìsíOctober 6, 1951(1951-10-06) (ọmọ ọdún 67)
Philadelphia
Ọmọ orílẹ̀-èdèJemánì
Pápáphysics and biochemistry
Ibi ẹ̀kọ́Strasbourg Heidelberg
Ó gbajúmọ̀ fúnIbasepo l'arin gbigbemi ategun ati igbekale iselopo agbara ti lactic acid ninu isan ara.
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physiology or Medicine, 1922[1]
Fellow of the Royal Society[2]

A bi Otto Fritz Mayerhof ni ilu Hannover ni Theaterplatz 16A (eyi ti o to di Rathenaustrasse 16A), osi je omo si awon obi juu oloro