Oyewusi Gureje, NNOM (tí a bí ní ọdún 1952) jẹ́ Dọ́kítà àwọn alárùn ọpọlọ tí NàìjíríàYunifásítì Ìbàdàn,[1] Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti olùdarí World Health Organization Ọ̀gbà Ìfọwọ́kowọ́ fún ìṣàwárí àti ìdánilẹ́kọ̀ọ́ nínu ọgbà ìlera, Neurosciences,Àmúpara Ògùn àti ọtí nínú ẹ̀ka ẹ̀kọ́ náà.[2] Ó tún jẹ́ amọ̀ye tó kúná àti Ọ̀jọ̀gbọ́n ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ arùn ọpọlọ ní ilé-ìwé ẹ̀kọ́ gíga Psychiatry, Stellenbosch University, South Africa.[3] Ó jẹ́ ẹni mímọ̀ dájú látàrí iṣẹ́ rẹ̀ lórí epidemiology, ẹ̀ka ìṣèwòsàn oríṣiríṣi àwọn àrùn àti ìlera ọlọ́pọlọ ti àgbáyé tí ń ṣe ọ̀kan lára àwọn adarí lórí àjọ iṣèwòsàn ọlọ́pọlọ àti ètò ìdàgbàsókè ti Áfíríkà. Oye Gureje ti ṣàgbéjáde ìwé tó ju ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta lórí àtúnyẹ̀wò ìmọ̀ sáyẹ́nsì, ìwé tó kúnjú òṣùwọ̀n, ìwé tó kún fún ìpele-ìpele àti àwọn ìwé àkójọpọ̀ ẹ̀sùn. Ó wà lára àwọn tí a yàn láti ọdún 2004, nínú ìdá kan lórí aṣèwádìí lórí iṣẹ́ rẹ̀ ìṣèwòsàn àrùn ọpọlọ àti psychology" and, according to Clarivate Analytics, he is one of the "most influential scientific minds"[2]

Ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Oyewusi Gureje, tí a bí ní Ilesa, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun,ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa ètò ìṣègùn ní Yunifásítì tí Benin, Nàìjíríà ní ìgbà díẹ̀ si, ó gba àmì ẹ̀yẹ másítà ti sáyẹ́nsì ní University of Manchester, UK.[1] Ó gba ìwé-ẹ̀rí (PhD) nínú ẹ̀kọ́ neuropsychiatry (Àkọ́lé iṣẹ́ àṣekágbá rẹ̀ ni: "The nosological status of schizophrenia”) ní University of Ibadan Ó tún tẹ̀síwájú láti gba " Doctor of Science" ní ilé ẹ̀kọ́ gíga kan náà. [4]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Gureje ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùkọ́-àgbà ní Yunifásítì Ìbàdàn, ó sì tún jẹ́ Olùdámọ̀ràn àwọn alárùn ọpọlọ ní Yunifásítì Kọ́lẹ́ẹ̀jì ilé-ìwòsàn láti ọdún 1989. Ó jẹ́ olórí ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ti ìṣèwòsàn àrùn ọpọlọ ní ilé ẹ̀kọ́ gíga méjèèjì láti ọdún 1999 – 2003 àti 2007 -2011.[5] Ní ọdún 2010, Ó ṣàgbéjáde the Mental Health Leadership and Advocacy Programme (mhLAP) ní ilé ẹ̀kọ́ gíga náà.[6]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 "Nigerian National Merit Award". www.meritaward.ng. Archived from the original on 2022-02-18. Retrieved 2020-05-28. 
  2. 2.0 2.1 Room, Robin (2013). "El alcohol y los países en desarrollo.". buscoinfobjcu.uca.edu.ni (in Spanish). Retrieved 2020-05-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "Extraordinary Appointments". www.sun.ac.za. Retrieved 2020-05-28. 
  4. "What do the University of Manchester and University of Manchester have in common?" Check |url= value (help). frontend. Retrieved 2020-05-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. "Search | Faculty of Psychiatry". www.dissertation.npmcn.edu.ng. Archived from the original on 2022-02-18. Retrieved 2020-05-28. 
  6. "About us – LCMHS" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-02-18. Retrieved 2020-05-28. 
  1. Prof. Oye Gureje Collaborating Centre for Research & Training in Mental Health, Neurosciences & Drug & Alcohol Abuse.(WHO). Retrieved 19 June 2019.
  2. Prof. Oye Gureje Extraordinary Appointments Stellenbosch University. Retrieved 19 June 2019.
  3. Prof. Oye Gureje https://web.archive.org/web/20190220122703/https://hcr.clarivate.com/
  4. Prof. Oye Gureje http://www.mhlap.org/
  5. Prof. Oye Gureje [1]
  6. Prof. Oye Gureje https://www.ghanaweb.com/GhanaHomePage/NewsArchive/Establish-mental-health-authority-MhLAP-276720[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  7. Prof. Oye Gureje https://allafrica.com/stories/201905030679.html
  8. Prof. Oye Gureje Global Clinical Practice Network - GCP.Network Leadership. Retrieved 19 June 2019.
  9. The Lancet (8 June 2019). "ICD-11". The Lancet 393 (10188): 2275. doi:10.1016/S0140-6736(19)31205-X. PMID 31180012. 
  10. Prof. Oye Gureje "The Lancet Series on Mental Health". Global Mental Health 2007 http://www.thelancet.com/series/global-mental-health
  11. Prof. Oye Gureje https://www.thelancet.com/commissions/quality-health-systems
  12. Prof. Oye Gureje https://www.youtube.com/watch?v=FoMr5BJ_W3U
  13. Prof. Oye Gureje https://mentalhealthcoalitionsl.com/partners/mhlap/
  14. Prof. Oye Gureje Nigerian National Merit Award" (NNOM). Retrieved 19 June 2019. http://www.meritaward.ng/ Archived 2020-03-06 at the Wayback Machine.
àtúnṣe

Research profile

àtúnṣe

Google Scholar Citations

ResearchGate Profile

Web of Science/Publons Profile

Àdàkọ:Authority control