Ọ̀yọ́

(Àtúnjúwe láti Oyo, Nigeria)

Ilu Ọ̀yọ́ jẹ́ ilu ni Naijiria. Àwọn tí ó ń gbé ìlú Ọ̀yọ́ jù ni àwọn ẹ̀ya Yorùbá, olóri ìlú Ọ̀yọ́ ni Ikú bàbá yèyé Aláàfin Ọba Làmídì Adẹ́yẹmí kẹ̀ta (III).

Ọ̀yọ́Coordinates: 7°51′00″N 3°55′59″E / 7.850°N 3.933°E / 7.850; 3.933