Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Agbalagba (2): Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Content deleted Content added
Yemi festus (ọ̀rọ̀ | àfikún) |
Àlẹ̀mọ́: Reverted |
||
Ìlà 5:
</div>
----
{{Àdàkọ:Afd top}}
====Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀====
<!-- sọ̀rọ̀ ṣóki nípa ìdí tí o fi fẹ́ fa oníṣẹ́ yìí sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí alábójútó-->
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá.
Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ ''Mo faramọ'' nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín. [[Oníṣe:Agbalagba|Agbalagba]] ([[Ọ̀rọ̀ oníṣe:Agbalagba|ọ̀rọ̀]]) 13:23, 9 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 (UTC)
{{Àdàkọ:Afd bottom}}
====Ìjíròrò====
|