Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò "Benin"

41 bytes added ,  22:07, 17 Oṣù Keje 2012
k
k (r2.7.2+) (Bot: Ìfikún sn:Benin)
== Oruko ==
 
"Benin" gege bi oruko re ko ni ohunkohun se pelu [[Ilẹ̀ọba Benin]] tabi [[Ilu Benin]] ni Naijiria. Oruko re tele je [[Dahomey]] (Dan-ejo (snake),Homey-Ilu,Ilu awon ejo) ki a to yi si Orile-ede Olominira Omoilu ile Benin ni odun 1975 nitori pe egbe odo to wa un je [[Etiodo Benin]]. Won mu oruko yi nitoripe ko fi s'egbe kan larin gbogbo awon eya eniyan bi adota ti won wa ni ile Benin. Dahomey je oruko iluoba [[Fon]] ti ayeijoun, nitori eyi won ro pe ko to.
 
== Ìtàn ==