Paul Émile Chabas: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Content deleted Content added
 
Ìlà 27:
 
Bíótilẹ̀jẹ́pé rògbòdìyàn yìí kò dáwọ́ dúró. Ní bíi ìkẹyìn ọdún 1935, àwọn ènìyàn gbọ́ ìró wípé ọmọbìrin tí ó jẹ́ àwòran yìí jẹ ẹnìkan tí ìyà ń jẹ́ tí ó n gba lẹ́tà láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn ní U.S tí ó maa ràn-àn lọ́wọ́. Ó tún rántí bí àwọn ènìyàn kan ní U.S ti sọ wípé àwòrán yìí kò bójú mu ní bíi ogún ọdún ṣ́yìn.<ref>{{cite news|url=https://www.newspapers.com/clip/1037729/chabas_dispels_september_morn_rumors/?|title=Artist Reveals Story of 'September Morn' Untrue|date=8 March 1935|page=6|publisher=The San Bernardino County Sun|via = [[Ancestry.com|Newspapers.com]]}}{{Open access}}</ref>
Chabas kọ́kọ́ lọ sí United States ní ọdún 1914 fún abala ìyàwòrán kan. Kí ó to rin ìrìnàjò yìí, ó sọ wípé oun kò fẹ́ran US, tí ó sì kọ̀ láti ta ''September morn'' fún olùtẹ̀jáde ìwé ìròyìn US, lẹ́yìn tí rògbòdìyàn nípa àwòrán yìí bẹ̀rẹ̀. Ó sọ wípé oun kò ní ìpinu láti ta àwòrán yìí, nítorí oun ni ìyàwó rẹ̀ fẹ́ràn jùlọ. Nígbà tí ó ọjà àwòran, ó dá ẹgbẹ̀rún lọ́nà mẹ́wá dọ́là lée lórí tí ó sì ní ìgbàgbọ́ wípé kò sí ẹni tí ó maa ràá. Leon Mantashev, ọmọ Alexander Mantashev, gbajúgbajà elépo ni ó fẹ́ ràá tí ó sì tàá fun.<ref name=visit>{{cite news|url=https://www.newspapers.com/clip/1024564/chabas_never_meant_to_sell_wifes/?|title="September Morn" Creator Coming|date=June 21, 1914|page=11|publisher=Oakland Tribune|accessdate=September 17, 2014|via = [[Ancestry.com|Newspapers.com]]}}{{Open access}}</ref>
 
== Gallery ==